Yoruba: 3rd term revision questions JSS2 2024
  • 1. 1. Ona meji ti arangbo pin si ni : arangbo
A) Nla ati kekere
B) Oke ati isele
C) Titobi ati tinrin
D) Kikun ati kekeke
E) Gun ati kukuru
  • 2. 2. Eya meji ti o te ilu Epe do ni ilu Ijebu_Epe ati ....
A) Ijebu_ife
B) Ijebu_Remo
C) Eti_okun
D) Eko_Epe
E) Ikorodu
  • 3. 3. Ilu Epe gbajumo fun....
A) Igbon sisin
B) Eja_pipa
C) Ode sise
D) Oko riro
E) Eran pipa
  • 4. 4. Gege bi ayoka yii see so fun wa, ekun melo ni o wa ni ipnle Eko?
A) Màrun
B) Mejo
C) Mefa
D) Meje
E) Merin
  • 5. 5. Ewo ninu orisii eja wonyii ni won ko daruko re ninu ayoka yii?
A) Lele
B) Titus
C) Aro
D) Obokun
E) Agbodo
  • 6. 6. Oriki ti won fun ilu Epe lati fihan pe ilu to eja po nibe ni
A) 'Epe olomi okun'
B) Epe olomi osa'
C) 'Epe eleran tutu'
D) 'Epe onipepe eja'
E) 'Epe eleja tutu'
  • 7. 7. Kinni idi ti eja pipa fi rorun ni ilu Epe? nitori pe
A) eja won ni ibomiran
B) omo wewe po nibe
C) awon okunrin po nibe
D) omi osa yii ka
E) awon agbe alaroje po nibe
  • 8. 8. Ede ti o gbile julo ni ilu Epe ni
A) Ikorodu
B) Ijebu
C) Eko
D) Ibadan
E) Awori
  • 9. 9. Odo wo ni won ti n pa eja ni ilu Epe?
A) Kanga
B) Okun
C) Osa
D) Lagoon
E) Odo-eran
  • 10. 10. Kinni o fa ifaseyin fun eto kara-kata eja pipa ati tita ni ilu Epe?
A) Awon apeja ti ku tan
B) Awon apeja to din ku
C) Awon apeja ko ri eja pa mo
D) Awon eja ti saalo tan
E) Awon apeja da ise sele
  • 11. 11. Ewo ninu awon wonyii ni o pon dandan ki o wa ninu leta aigbefe?
A) Adiresi
B) Ikinni
C) Koko oro
D) Ikadi
E) Akole
  • 12. 12. Ewo ninu awon wonyii ti o lee wa ninu leta gbefe?
A) adiresi
B) Ikinni
C) Koko oro
D) awada
E) akole
  • 13. 13. Konsonanti aranmupe asesilebu ni
A) en
B) n
C) an
D) en
E) on
  • 14. 14. Ihun silebu ' akekoo' ni
A) FK-Fk-FF-K
B) FK-FK-FF
C) F-KFK-FF
D) F-KF-KF-F
E) FKF-KFF
  • 15. 15. Orisa to maa n yo Ina lenu ni
A) Agemo
B) Esu
C) Oya
D) Sango
E) Yemoja
  • 16. 16. Ewo ni ohun eelo isomoloruko ninu awon wonyii?
A) Bata
B) Elubo
C) Atike
D) Ataare
E) Aso
  • 17. 17. Ewo ni o wa fun ayeye ninu awon Isare wonyii?
A) Bolojo
B) Iyere ifa
C) Iwi
D) Esa
E) Esu pipe
  • 18. 18. Ohun pipe ti awon babanla wa n lo nibi esin orisa ati ayeye ti ko je mo esin orisa ni
A) Aruge
B) Ayajo
C) Ofo
D) Isare
E) Awigbo
  • 19. 19. Afo ti a fi ohun to dun ni eti ko sits ni
A) Esa
B) Orin
C) Epe
D) Afose
E) Eebu
  • 20. 20. Irufe litireso wo ni won kii ko sile, sugbon ti won maa gbe jade lati Inu opolo? Litireso
A) atijo
B) alohun
C) akanse
D) apileko
E) igbalode
  • 21. 21. Orin to a n ko lati je ki omode dake nigba ti o n sunkun ni Orin
A) Eremode
B) Okoyawo
C) Faaji
D) Igbeyawo
E) Aremolekun
  • 22. 22. Okan ninu isori litireso alohun ni
A) Ewi
B) Leta gbefe
C) Isare
D) Akoto
E) Yoruba
  • 23. 23. Orisii aalo ti o ni orin ninu ni aalo
A) isare
B) apomo
C) efe
D) apagbe
E) ariwo
  • 24. 24. Iyere ifa ati Esa je Isare ti won n lo nibi
A) esin Ibile
B) ibudoko
C) isinku
D) ile -iwe
E) ile ounje
  • 25. 25. Isori oro melo ni a ni ninu ede Yoruba?
A) Mewa
B) Mesan
C) Meje
D) Mokanla
E) Mejo
  • 26. 26. Egbawa ni figo je
A) 1500
B) 2000
C) 4000
D) 3000
E) 5000
  • 27. 27. ( 200 x 4) +44=
A) Ojile legberi. o le merin
B) Orin le legberin
C) Ojile le legbefa
D) Egberin
E) Eedegbeta
  • 28. 28. Silebu melo ni o wa ninu'gbogbonise'
A) Mejo
B) Mefa
C) Marun
D) Merin
E) Meje
  • 29. 29. Ewo ninu awon wonyii ni ko si lara ohun eelo ti a fi n jagun?
A) Kondo
B) Ibon
C) Kannakan
D) Ofa
E) Aga
  • 30. 30. Ewo ninu awon wonyii ni kii se esin ode-oni? Esin
A) Ekanka
B) Gurumarji
C) Buda
D) Ibile
E) Kirisiteni
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.