Ede Yoruba :2nd Term Exam 2024 Grade 5&6
  • 1. 2. Ege oro ti o kere julo ti eemi lee gbe jade leekan soso ni.,.,
A) Silebu
B) Aroso
C) Gbolohun
D) Alaye
E) Iroyin
  • 2. 3. Silebu melo ni o wa ninu oro yii-alapansanpa ?
A) Meta
B) Merin
C) Meji
D) Mefa
E) Marun
  • 3. 4. Ewo ni oro oni silebu kan ninu awon won yii?
A) Sere
B) Igbo
C) Kondo
D) Atata
E) Gbon
  • 4. 5. Orisii batani silebu melo ni o wa ninu ede pYoruba
A) Mefa
B) Merin
C) Meta
D) Meje
E) Marun
  • 5. 6. So ihun oro yii -ate
A) KKK
B) KKF
C) FKF
D) FFK
E) KFK
  • 6. 7. Kin ni itumo ihun oro yii - KF?
A) Faweeli + Faweeli
B) Konsonanti + Faweeli
C) Faweeli + konsonanti
D) Konsonanti + Konsonanti
E) Konsonanti + Faweeli+ konsonanti
  • 7. 8. Ise loogun .......
A) Ole
B) Owo
C) Oga
D) Ise
E) Ebi
  • 8. 9. Mura....,... Ore mi
A) Soro
B) Sosi
C) Sise
D) Sigberaga
E) Sole
  • 9. 10. Ise la fi n deni ........
A) Daadaa
B) Giga
C) Kukutu
D) Etan
E) Yepere
  • 10. 11. Bi a ko ba reni........ ti
A) Soro
B) Foriti
C) Farakin
D) Fojujo
E) Feyin
  • 11. 12. Bi .... la n ri
A) Gbajumo
B) Olola
C) Ole
D) Olowo
E) Olomi
  • 12. 13. Bi a ko ba reni...,... le
A) Gboju
B) Gbara
C) Gbokan
D) Gbeti
E) Gbenu
  • 13. 15. A tera ......... eni
A) mose
B) momele
C) mako
D) mora
E) mole
  • 14. 16. Ewo ni asa imototo nínu awon won yii?
A) Yiyagbe si inu yara
B) Fifo abo si Ori ibusun
C) Dida ile si iwaju ile
D) Wiwe ara
E) Tito si inu yara
  • 15. 17. Awon ona won yii ni a lee gba toju ayika wa, ayafi
A) titoju oju ogbara lati je ki omi idati lo geere
B) didale si iwaju ile
C) ile gbigba
D) sisan oko ti o ba kun
E) tiro oko ayika ile
  • 16. 18. Awon won yii ni a lee lo lati fi tun ayika wa se, ayafi
A) telifonu
B) reeki
C) oko
D) igbale
E) ada
  • 17. 19. Gbigbin ododo maa n mu ki ayika.......
A) rewa
B) fa esinsin
C) maa ru
D) da arun sile
E) mu ki arun wole
  • 18. 20. Iwa obun maa n fa ....... si ara
A) alaafia
B) ayo
C) ibukun
D) aisan
E) ifayabale
  • 19. 21. 30 ni onka Yoruba je
A) Aadorun
B) Ogofa
C) Aadota
D) Ogbon
E) Ogoji
  • 20. 22. Ogofa ni figo je
A) 110
B) 120
C) 50
D) 80
E) 200
  • 21. 23. Baba ni ..,..., ninu ebi
A) baale
B) oloro
C) daodu
D) akobi
E) alejo
  • 22. 24.. Ta ni o maa n pari ija ti o ba sele ninu ebi
A) Iyawo
B) Obakan
C) Olori ebi
D) Daodu
E) Baale
  • 23. 25. Ojuse gbogbo molebi ni lati to awon....... sona ododo
A) iyawo
B) omode
C) obinrin
D) okunrin
E) agbalagba
  • 24. 26. Iyawo ti won koko fe wo inu ebi kan ni.,..
A) iyale
B) ale
C) ibatan
D) afesona
E) babale
  • 25. 27. Egbon tabi aburo baba tabi iya lokunrin tabi lobinrin ni ..,..
A) onkulu
B) ibatan
C) egbon
D) aburo
E) iyekan
  • 26. 28. Akojopo awon eniyan ti won ni ajosepo nipa ibi ni.......
A) egbon
B) aladugbo
C) alabagbe
D) ore
E) ibatan
  • 27. 29.. Awon ebi maa n da aso kan naa lati fi sami....... laarin won
A) ija
B) aisowo
C) wahala
D) ikorira
E) ife
  • 28. 30. Ewo nínu awon won yii ni o ni batani ihun KF-KF?
A) Ewe
B) Gbe
C) Ori
D) Omi
E) Tete
  • 29. 31. Obinrin ti oko re ku ni.,....
A) Iya agba
B) Iyawo
C) Omoge
D) Iyale
E) Opo
  • 30. 32 Egbon ati aburo lati odo baba kan naa ni
A) Alabagbe
B) Iyekan
C) Molebi
D) Ore
E) Obakan
  • 31. 33. Akobi obinrin ni agboole kan ni....
A) Anti
B) Aburo
C) Omo obinrin
D) Egbon
E) Beere
  • 32. 34. Omo iya kan naa ni....,
A) Ibatan
B) Molebi
C) Ojulumo
D) Ebi
E) Iyekan
  • 33. 35. Akobi oba lokunrin ni.,
A) Aremo
B) Omo olori
C) Omo baba
D) Omo oye
E) Omooba
  • 34. 36. 27 ni onka Yoruba je
A) Eeta din logbon
B) Eeta le logun
C) Eeta din logun
D) Eeta din laadota
E) Eeta le logbon
  • 35. 37. Ookan le logorun ni
A) 401
B) 101
C) 501
D) 301
E) 201
  • 36. 38. Aise imoto ounje lee fa...,
A) Aileesun
B) Apple
C) Idunnu
D) Aisan
E) Oriire
  • 37. 39. Ewo ni a lee ri ile idanna?
A) Abo
B) Ade
C) Ada
D) Ikole
E) Owo
  • 38. 40 . 60 ni onka je
A) Ogorin
B) Aadorun
C) Aadota
D) Aadorinr
E) Ogota
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.