- 1. 1. Nínú ìwe alawiiye, (akọle : ogun idanwo)tani o mu awọn ọmọ lọ sì ile onisegun
A) Bọla B) Bọsẹ C) Ẹgbọn bọsẹ D) Dupẹ
- 2. 2. Nínú akole ogun idanwo ìwe alawiiye...awọn wo ni wón ro pe awọn yóò gbà gbogbo maaki tan
A) Bọsẹ ati dupẹ B) Ẹgbọn Bola C) Bola D) Tolani
- 3. 3.ninu iwe alawiiye akọle ogun idanwo..Ta ni kogba pe ogun idanwo n bẹ
A) Ẹgbọn bọsẹ B) Bọla C) Dupẹ D) Ṣeṣan
- 4. 4. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo.. ẹni tí inú rẹ dùn bí se ka ìwé ibeere idanwo ni..........
A) Bọsẹ B) Ẹgbọn bọsẹ C) Dupẹ D) Bọla
- 5. 5. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo...tani o sọ pe ohun dáràn ninu yara idanwo
A) Bọsẹ B) Ẹgbọn bọsẹ C) Dupẹ D) Bọla
- 6. 6.ninu iwe alawiiye akọle ọwọ ẹyin....iye awọn orukọ orisirisi ti a pè owo ẹyin nínú ẹkọ yìí jẹ
A) Mewa B) Mẹfa C) Meje D) Marun
- 7. 7. Nínú ìwe alawiiye akọle owo ẹyin... Ọkan nínú awọn nkan ti awọn eniyan n fi dipò owó abẹtẹlẹ ni
A) Suuru B) Igberaga C) Faari D) Ara wọn
- 8. 8. Gbólóhùn alabọde ni a tún mọ Si......
A) Ọlọpọ ọrọ ise B) Aṣẹ C) Alakanpọ D) Ẹlẹyọ ọrọ ìse
- 9. 9. Àpẹẹrẹ ọrọ ìse yii.(..........) Le duro' gẹgẹ bí gbólóhùn alabọde
A) Si B) Jade C) Na D) Jẹ
- 10. 10. Ẹni tabi ohun tí o se nnkan nínú gbólóhùn ni.........
A) Ẹyàn B) Ẹpọn C) Oluwa D) Abọ
- 11. 11. ........ Ni ẹni tabi ohun tí a ṣe nnkan Si nínú gbólóhùn
A) Abọ B) Oluwa C) Ẹpọn D) Ẹyàn
- 12. 12. ......... Ni a mọ sì ọrọ tabi atopọ tí o n gbé oye tabi ero kíkún jade
A) Silebu B) Lẹta C) Ọrọ ise D) Gbólóhùn
- 13. 13. Adirẹsi mélòó ni lẹta gbẹfẹ ni
A) Mẹrin B) Mẹta C) Ọkan D) Meji
- 14. 14. Lẹta...... Kí i ni akọle
A) Gbẹfẹ B) Aṣẹ C) Aigbagbẹfẹ D) Iroyin
- 15. 15. Ọwọ........ Ni adirẹsi ma n wa
A) Ọtun B) Osi C) Iwaju D) Ẹyin
- 16. 16. Ipin mélòó ni lẹta Pin si
A) Meji B) Marun C) Mẹta D) Merin
- 17. 17. ......... Ni ọna àròkọ ti a ma n Gba sọ ohun to wa nínú wa Si ẹlòmíràn yala boya ololufẹ ẹni tabi òbí ẹni tabi ọgá ile isẹ kan
A) Ọrọ B) Lẹta C) Gbólóhùn D) Silebu
- 18. 18. Ọrẹ mí ọwọn jẹ.............nínú lẹta gbẹfẹ
A) Ibuni B) Inifẹ ẹni C) Ipọnni D) Ìkíni
- 19. 19. ...... lẹta ti aa n kọ Si awọn ènìyàn ti wọn wa ni ipò kan ni ibi isẹ aladani tabi Si àjọ ilu
A) Iroyin B) Aigbagbẹfẹ C) Gbẹfẹ D) Aṣẹ
- 20. 20. Lara awọn ti a ma n kọ lẹta aigbagbẹfẹ Si ni awọn wọnyi ayafi....
A) Olootu ìwe iroyin B) Ololufẹ ẹni C) Alága ìjọba ìbílẹ̀ D) Giwa ile isẹ
- 21. 21. Adirẹsi mélòó ni lẹta aigbagbẹfẹ ma n ni
A) Mẹta B) Meji C) Mẹrin D) Ẹyọkan
- 22. 22. Kínní 195 ni èdè yorúbá
A) Marundinigba B) Meedofa C) Marunlenigba D) Ọgọwa
- 23. 23.bawo ni ase lé pe figọ yìí lede yorúbá 170
A) Aadọwa B) Ọgọsan C) Aadọsan D) Ọgọwa
- 24. 24. Aadọwa ni figọ jẹ....
A) 190 B) 200 C) 170 D) 160
- 25. 25. Orukọ miran fún ọgọwa ni....
A) Okanlelọgọfa B) Ọdunrun C) Igba D) Ọkanlaadofa
- 26. 26. Ìtumọ lẹta gbẹfẹ ni ede gẹẹsi ni...
A) Package letter B) Informal letter C) Formal letter D) Semi formal letter
- 27. 27. Ìtumọ gbólóhùn alabọde ni èdè gẹẹsi ni.......
A) Compound sentence B) Simple sentence C) Compound complex sentence D) Complex sentence
- 28. 28. Ìtumọ gbólóhùn alakanpọ ni èdè gẹẹsi ni..........
A) Complex sentence B) Compound sentence C) Simple sentence D) Compound complex sentence
- 29. 29. Ìtumọ lẹta aigbẹfẹ ni èdè gẹ̀ẹ́sì ni.........
A) Semi formal letter B) International letter C) Formal letter D) Informal letter
- 30. 30. 99 ni onka yoruba jẹ........
A) Ọkandinlọgọrun B) Ọkandinladọrun C) Ọkanlelọgọrun D) Ọkanlelaadọrun
|