- 1. 1. Nínú ìwe alawiiye, (akọle : ogun idanwo)tani o mu awọn ọmọ lọ sì ile onisegun
A) Bọla B) Ẹgbọn bọsẹ C) Dupẹ D) Bọsẹ
- 2. 2. Nínú akole ogun idanwo ìwe alawiiye...awọn wo ni wón ro pe awọn yóò gbà gbogbo maaki tan
A) Bọsẹ ati dupẹ B) Ẹgbọn Bola C) Tolani D) Bola
- 3. 3.ninu iwe alawiiye akọle ogun idanwo..Ta ni kogba pe ogun idanwo n bẹ
A) Ṣeṣan B) Bọla C) Dupẹ D) Ẹgbọn bọsẹ
- 4. 4. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo.. ẹni tí inú rẹ dùn bí se ka ìwé ibeere idanwo ni..........
A) Ẹgbọn bọsẹ B) Bọsẹ C) Bọla D) Dupẹ
- 5. 5. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo...tani o sọ pe ohun dáràn ninu yara idanwo
A) Bọla B) Bọsẹ C) Ẹgbọn bọsẹ D) Dupẹ
- 6. 6.ninu iwe alawiiye akọle ọwọ ẹyin....iye awọn orukọ orisirisi ti a pè owo ẹyin nínú ẹkọ yìí jẹ
A) Mewa B) Mẹfa C) Marun D) Meje
- 7. 7. Nínú ìwe alawiiye akọle owo ẹyin... Ọkan nínú awọn nkan ti awọn eniyan n fi dipò owó abẹtẹlẹ ni
A) Ara wọn B) Igberaga C) Suuru D) Faari
- 8. 8. Gbólóhùn alabọde ni a tún mọ Si......
A) Ọlọpọ ọrọ ise B) Aṣẹ C) Alakanpọ D) Ẹlẹyọ ọrọ ìse
- 9. 9. Àpẹẹrẹ ọrọ ìse yii.(..........) Le duro' gẹgẹ bí gbólóhùn alabọde
A) Jade B) Jẹ C) Si D) Na
- 10. 10. Ẹni tabi ohun tí o se nnkan nínú gbólóhùn ni.........
A) Abọ B) Ẹyàn C) Ẹpọn D) Oluwa
- 11. 11. ........ Ni ẹni tabi ohun tí a ṣe nnkan Si nínú gbólóhùn
A) Oluwa B) Abọ C) Ẹyàn D) Ẹpọn
- 12. 12. ......... Ni a mọ sì ọrọ tabi atopọ tí o n gbé oye tabi ero kíkún jade
A) Silebu B) Ọrọ ise C) Lẹta D) Gbólóhùn
- 13. 13. Adirẹsi mélòó ni lẹta gbẹfẹ ni
A) Mẹrin B) Mẹta C) Ọkan D) Meji
- 14. 14. Lẹta...... Kí i ni akọle
A) Iroyin B) Aigbagbẹfẹ C) Gbẹfẹ D) Aṣẹ
- 15. 15. Ọwọ........ Ni adirẹsi ma n wa
A) Osi B) Iwaju C) Ọtun D) Ẹyin
- 16. 16. Ipin mélòó ni lẹta Pin si
A) Marun B) Merin C) Mẹta D) Meji
- 17. 17. ......... Ni ọna àròkọ ti a ma n Gba sọ ohun to wa nínú wa Si ẹlòmíràn yala boya ololufẹ ẹni tabi òbí ẹni tabi ọgá ile isẹ kan
A) Gbólóhùn B) Ọrọ C) Lẹta D) Silebu
- 18. 18. Ọrẹ mí ọwọn jẹ.............nínú lẹta gbẹfẹ
A) Inifẹ ẹni B) Ìkíni C) Ipọnni D) Ibuni
- 19. 19. ...... lẹta ti aa n kọ Si awọn ènìyàn ti wọn wa ni ipò kan ni ibi isẹ aladani tabi Si àjọ ilu
A) Aigbagbẹfẹ B) Gbẹfẹ C) Aṣẹ D) Iroyin
- 20. 20. Lara awọn ti a ma n kọ lẹta aigbagbẹfẹ Si ni awọn wọnyi ayafi....
A) Giwa ile isẹ B) Alága ìjọba ìbílẹ̀ C) Ololufẹ ẹni D) Olootu ìwe iroyin
- 21. 21. Adirẹsi mélòó ni lẹta aigbagbẹfẹ ma n ni
A) Meji B) Mẹta C) Ẹyọkan D) Mẹrin
- 22. 22. Kínní 195 ni èdè yorúbá
A) Ọgọwa B) Marundinigba C) Marunlenigba D) Meedofa
- 23. 23.bawo ni ase lé pe figọ yìí lede yorúbá 170
A) Aadọwa B) Ọgọsan C) Aadọsan D) Ọgọwa
- 24. 24. Aadọwa ni figọ jẹ....
A) 170 B) 190 C) 160 D) 200
- 25. 25. Orukọ miran fún ọgọwa ni....
A) Igba B) Ọdunrun C) Ọkanlaadofa D) Okanlelọgọfa
- 26. 26. Ìtumọ lẹta gbẹfẹ ni ede gẹẹsi ni...
A) Package letter B) Informal letter C) Formal letter D) Semi formal letter
- 27. 27. Ìtumọ gbólóhùn alabọde ni èdè gẹẹsi ni.......
A) Compound complex sentence B) Complex sentence C) Compound sentence D) Simple sentence
- 28. 28. Ìtumọ gbólóhùn alakanpọ ni èdè gẹẹsi ni..........
A) Complex sentence B) Compound complex sentence C) Simple sentence D) Compound sentence
- 29. 29. Ìtumọ lẹta aigbẹfẹ ni èdè gẹ̀ẹ́sì ni.........
A) International letter B) Semi formal letter C) Informal letter D) Formal letter
- 30. 30. 99 ni onka yoruba jẹ........
A) Ọkandinladọrun B) Ọkandinlọgọrun C) Ọkanlelaadọrun D) Ọkanlelọgọrun
|