AIC Yoruba 1st Term Exam for JS 1
  • 1. ___ni ege ti èémí le gbé jáde lẹkan ṣoṣo
A) Konsonanti
B) Sílébù
C) Ọ̀rọ̀
D) Faweeli
  • 2. Álífábẹ́ẹ̀tì èdè Yorùbá jẹ́____
A) 24
B) 25
C) 19
D) 18
  • 3. Kọ́nsónántì inú álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá jẹ́___
A) 18
B) 7
C) 20
D) 5
  • 4. Álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá pín sí____
A) Mérin
B) Méjì
C) Méta
D) Márùn-ún
  • 5. Ọ̀rọ̀ tí oní fáwèlì àìrànmúpè ni___
A) Wọn
B) Àwọn
C) Ara
D) Ìyẹn
  • 6. 20+30 ni Òǹkà Yorùbá jẹ́____
A) Ọgbọ̀n
B) Ogún
C) Ogójì
D) Àádọ́ta
  • 7. Ogójì ni____
A) 50
B) 30
C) 20
D) 40
  • 8. Bàbá, ìyá àti ọmọ méjì jẹ́ eniyan____
A) Méjì
B) Kan
C) Mérin
D) Meji
  • 9. Ètè méjì ní a fi pe kọ́ńsonáǹtì____
A) F
B) B
C) S
D) R
  • 10. /r/ jẹ́ kóńsónáǹtì____
A) Arẹ́họ́n
B) Àrańmúpè
C) Àfúnupè
D) Àséésetán
  • 11. Mélòó ni fáwẹ̀lì àìránmúpè Yorùbá?
A) Márùn-ún
B) Mẹ́ta
C) Mérin
D) Méje
  • 12. Ọgọ́rùn-ún ni ___
A) 80
B) 100
C) 60
D) 70
  • 13. Igba ni òǹkà Yorùbá ni ___
A) 100
B) 300
C) 500
D) 200
  • 14. Ohun tí a fi ń mọ iye sílébù tí ọ̀rọ̀ ní ni ___
A) Kóńsónáǹtì
B) Àmì ohùn
C) Ìró èdè
D) Fáwẹ̀lì
  • 15. Ọ̀rọ̀ onísílébù méjì ni ____
A) Yín
B) Wọn
C) Fún
D) Ìyá
  • 16. Ìrànlọ́wọ́ jẹ́ ọ̀rọ̀ onísílébù...
A) Mẹ́ta
B) Mẹ́rin
C) Mẹ́fà
D) Mẹ́rin
  • 17. A pín 'Alábahun' sí sílébù yìí
A) Alába-hun
B) A-lá-ba-hun
C) Ala-bahun
D) Alá-ba-hun
  • 18. Ọ̀rọ̀ onísílébù kan ni __
A) Rán
B) Ìyá
C) Ìwé
D) Bàbá
  • 19. Fáwẹ̀lì yìí kìí ṣe ti Yorùbá
A) ea
B) i
C) ọ
D) a
  • 20. Pín ọ̀rọ̀ yìí sí sílébù: Ìgbálẹ̀
A) Ìg-bálẹ̀
B) Ìg-bá-lẹ̀
C) Ìgbá-lẹ̀
D) Ì-gbá-lẹ̀
  • 21. Ìwé méjì àti ìwé mẹ́ta jẹ́ ìwé_____.
A) mẹ́rin
B) mẹ́ta
C) méjì
D) márùn-ún
  • 22. Àádọ́rin ní òǹkà Yorùbá ni_____.
A) 70
B) 30
C) 40
D) 50
  • 23. Tí a bá ro 20+10, o jẹ____
A) ogún
B) ọgbọ̀n
C) ọgọ́rin
D) àádọ́ta
  • 24. Lẹ́tà tí a pè nígbà tí eyín òkè àti ètè ìsàlẹ̀ pàdé ni_____.
A) f
B) gb
C) w
D) n
  • 25. Ìgbà tí a pe fáwẹ̀lì àrańmúpè, èémí gba ihò____ jáde.
A) ojú
B) ẹtì
C) imú
D) ahọ́n
  • 26. Fáwẹ̀lì àyanupè ni_____.
A) e
B) i
C) a
D) u
  • 27. Olùkó jẹ́ ọ̀rọ̀ onísílébù mélòó?
A) Mẹ́ta
B) Mẹ́rin
C) Márùn
D) Méjì
  • 28. Fáwẹ̀lì_____ni fáwẹ̀lì tí a kò ránmú pè.
A) àrańmúpè
B) àìránmúpè
C) un
D) kọ́ńsónáǹtì
  • 29. Fáwẹ̀lì____ni fáwẹ̀lì tí a ránmú pè.
A) iwaju
B) àrańmúpè
C) àìránmúpè
D) àhánupè
  • 30. 'Olu came first' túmọ̀ sí 'Olú ṣe ipò_____
A) kejì
B) kàrún
C) kìn-ín-ní
D) kẹta
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.