PES JSS 2 Yoruba 3rd Test 2024/25
  • 1. 1. Apeere isaare ajemesin ni
A) Obintu
B) Ekun Iyawo
C) Iyere ifa
  • 2. 2. Egberun ni figo ni
A) 2000
B) 1000
C) 3000
  • 3. 3. 1100
A) Eedegberin
B) Eedegbejo
C) Eedegbefa
  • 4. 4. 500 je.... ni onka
A) Egbefa
B) Eedegberin
C) eedegbeta
  • 5. 5. 100 + 78 =
A) Eeji din legbeta
B) Eeji din logosan
C) Eeji le nigba
  • 6. 6. Tani olori awọn to n bo sango?
A) Abore
B) Alapata
C) Adosu
  • 7. 7. A maa n.....ijala
A) Ko
B) Sun
C) Wi
  • 8. 8. Ewo ni eewo orisa esu ninu awọn won yii?
A) Omi
B) Eja
C) Adi
  • 9. 9. Iru eniyan wo ni o n sun ekun Iyawo?
A) Omobinrin ti o n lo sile oko
B) Obintin to bimo ku
C) Iya Iyawo
  • 10. 10. Ewo ni isaare ajemesin ninu awọn won yii
A) Sango pipe
B) ijala
C) Bolojo
  • 11. 11. Ewo ni kii se ona Iran ra eni lowo ni aye atijo ninu awọn ona Iran ra eni lowo won yii?
A) Itufu
B) Owe
C) Aaro
  • 12. 12. Ewo ni oro oruko ti o sise abo ninu gbolohun yii "Kola je eja"
A) Kola
B) Je
C) Eja
  • 13. 13. Kini oro ise ti o wa ninu gbolohun yii "Ade lo si Abuja"
A) si
B) lo
C) Abuja
  • 14. 14. Ewo ni oro aropo oruko ninu gbolohun yii "Mo ra aso aran"
A) ra
B) aran
C) Mo
  • 15. 15. Kini akole iwe litireso ti a n ka ni kilaasi fun saa yi?
A) Owo Agbaraa
B) Igba Otun
C) Olori Asake
  • 16. 16. Tani onkowe iwe itan naa ?
A) Abiodun Alabama Aina
B) Olaleye Rukayat Adeyemi
C) Wasiu Akinpelu Ganiyu
  • 17. 17. Kini oruko baba Kofo ninu iwe itan naa?
A) Alade
B) Ifasina
C) Kuponu
  • 18. 18. Kini oruko inagije ti awọn eniyan maa n pe Alabi?
A) Olowookere
B) Olowonjo
C) Olohunyo
  • 19. 19. Kini idi to Kofo ko fi nife lati kawe, kose tabi se owo kankan? Nitori pe,
A) O gboju le owo to baba re
B) O ti dagba ju ile iwe lo
C) Awọn okunrin n yoo lenu
  • 20. 20. Iyawo melo ni o wa ni ile Alabi bayi?
A) Meta
B) Eyo kan
C) Merin
Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.