JS 3 Ede Yoruba: 1st Term
  • 1. 1. Parts of speech ni ede Yoruba ni
A) Akole oro
B) Isori oro
C) Apa oro
D) Ipin oro
E) Eyan oro
  • 2. 2. Preposition tumo si oro............ni ede Yoruba
A) Aponle
B) Ise
C) Asopo
D) Atokun
E) Asapejuwe
  • 3. 3. Ewo ni isare ajemayeye ninu awon oro wonyi?
A) Ekun iyawo
B) Esa
C) Ijala
D) Oya pipe
E) Iyere
  • 4. 4. Orisa wo ni won n ki pe " laalu ofiri oko"
A) Sango
B) Oya
C) Ogun
D) Esu
E) Obatala
  • 5. 5. Esin wo ni kii se esin ode oni ninu awon wonyii? Esin
A) Ibile
B) Islam
C) Ekànka
D) Kirisiteni
E) Guru
  • 6. 6. Odun wo ni awon omo leyin Jesu maa n se ninu osu kejila? Odun
A) Ileya
B) Keresimesi
C) Aawe
D) Tuntun
E) Esita
  • 7. 7. Ki ni oruko awon omo meji ti iya kan bil leekannaa ni ojo kan soso?
A) Idowu
B) Idogbe
C) Ibeji
D) Alaba
E) Ibeta
  • 8. 8. Ewo ninu awon oruko wonyii ni awon Yoruba maa n pe omo tuntun?
A) Ikoko
B) Ige
C) Apeke
D) Ibeji
E) Aadamo
  • 9. 9. Ewo ni nnkan eelo isomoloruko ni ile Yoruba ninu awon wonyii?
A) Igbale
B) Elubo
C) Igi
D) Omi
E) Ata
  • 10. 10. 600 ni onka je
A) Egbefa
B) Egbewa
C) Aadorun
D) Egbeta
E) Egberun
  • 11. 11. Aadofa ni figo je
A) 1110
B) 110
C) 111
D) 101
E) 131
  • 12. 12. Eeta le laadorun je
A) 83
B) 53
C) 93
D) 73
E) 63
  • 13. 13. Meedogun + eeta din logoji=
A) Eeji le laadota
B) Erin le logun
C) Aarun din laadota
D) Aarun din logorin
E) Eeta din logbon
  • 14. 14. Otaleerugba din marun je
A) 245
B) 225
C) 215
D) 235
E) 255
  • 15. 15. 800 je....... ni onka
A) Eedegbeta
B) Egbefa
C) Egberin
D) eedegbesan
E) Egbewa
  • 16. 16. Orin le nirinwo din marun je
A) 280
B) 420
C) 520
D) 350 nirinwo
E) 475
  • 17. 17. Igbeyawo ode oni pin si ona
A) Meji
B) Merin
C) Meta
D) Aimoye
E) Marun
  • 18. 18. Iru igbeyawo wo ni pko iyawo ko gbodo fe iyawo miran leyin asopo won gege bii oko ati iyawo? Igbeyawo
A) Kootu
B) Soosi
C) Tiwantiwa
D) Masalaasi
E) Ibile
  • 19. 19. Ilana melo ni o wa ninu Igbeyawo ibile?
A) Mata
B) Mefa
C) Mewa
D) Mesan
E) Mejo
  • 20. 20. Ninu Igbeyawo mosalasi, tani o maa n so yigi laarin oko ati iyawo?
A) Baba iyawo
B) Pasito
C) Baba oko
D) Olori ebi
E) Alufaa
  • 21. 21. Ninu asa igbeyawo ni ile Yoruba, tani o maa n san owo ori iyawo?
A) Oko iyawo
B) Baba iyawo
C) Ebi oko
D) Ore oko
E) Ebi iyawo
  • 22. 22. Ewu wo ni o lee wa, ti oko ko ba ba iyawo re nile?
A) O lee fa ipinya laarin oko ati iyawo
B) Inu iyawo yoo maa dun
C) Ibeji ni iyawo yoo maa bi
D) Iyawo yoo tete loyun
E) Inu oko yoo maa dun
  • 23. 23. Ewo ninu awon nnkan wonyii ni o maa n fi se idana ni ile Yoruba?
A) Owu
B) Ata
C) Ose
D) Owo
E) Kankan
  • 24. 24. Ti okunrin tabi obinrin ba ti dagba to eni ti o lee feyawo tabi loko ni Yoruba n pe ni
A) Balaga
B) Gbon
C) Laju
D) Dagba
E) Moye
  • 25. 25.......... ni ki omobinrin ma tii ni ibalopo kankan . titi ti yo fi lo si ile oko re
A) Itoju
B) Balaga
C) Ibale
D) Ipinnu
E) Amojuto
  • 26. 26. Gbigbe ohun ti a n ta si oju kan fun onibara lati ri, ki o si nife lati raa ni
A) Ifihan oja
B) Ipalemo oja
C) Atokun oja
D) Itowo oja
E) Ipate oja
  • 27. 27. Agbenuso laarin oko ati iyawo ni
A) Alarena
B) Agbenuso
C) Alagbaso
D) Olubadamoran
E) Alamojuto
  • 28. 28. kiko ebun lo si ile iyawo lati odo awon ebi oko ni a n pe ni
A) Idana
B) Igbeyawo
C) Ijehen
D) Iwadi
E) Isegiri leekannaa
  • 29. 29. A maa n fi ataare se adura nibi
A) Isinku
B) Odun eegun
C) Igbeyawo
D) Isomoloruko
E) Oye jije
  • 30. 30. 398 je......ni onka Yoruba
A) Eeji din nirinwo
B) Aarun din loodunrun
C) Aarun din nigba
D) Eeji le nirinwo
E) Eerin le nigba
  • 31. 31. Iru leta wo ni a n ko si oga ile ise ijoba? Leta
A) Adako
B) Abaniwase
C) Gbefe
D) Itewa
E) Aigbefe
  • 32. 32. Iru eni wo ni a lee ko leta gbefee si?
A) Ore
B) Oga Ile ise
C) Ile ise ijoba
D) Oga Ile ifowopamo
E) Oga Ile eko
  • 33. 33. Ewo ninu awon wonyii ni o lee fa airisese?
A) Akitiyan lati da si idagbasoke ilu
B) Tite siwaju lori eko
C) Inife si owo sise
D) Nini Ife si owo lai sise
E) Itepamose
  • 34. 34. Awon wo ni airisese wopo ni aarin won? Awon
A) Okunrin'
B) Arugbo
C) Alakowe
D) Odo
E) Omode
  • 35. 35. Airisese lee fa ki eniyan
A) Maa se ofofo
B) Ma lee jeun daadaa
C) Ma bowo fagba
D) Sanra
E) Pokunso
  • 36. 36. Ipolowo oja mu ki ontaja
A) Ki gbese Po
B) Ki awon onibara ma ra oja mo
C) Ki ere po sii
D) Ontaja ma ri oja ta
E) ni onibara pupo sii
  • 37. 37. Owe Yoruba so pe, " owo ti ada ba mo....... "
A) "lo n je ki o ku lenu"
B) "lo n baa je"
C) "lo n kaa leyin"
D) "lo n daa lagara"
E) "lo je ki o sonu"
  • 38. 38. Ko lo nile, kowo de, iru oja won ni maa n polowo bayii?
A) Gaari
B) Aso
C) Isu
D) Agbado
E) Oyin
  • 39. 39. Bayi ni a se maa n polowo iyan
A) Iyan ire, obe ire
B) E rayan , e jeun o
C) Oniyan n lo ile
D) E woju obe ,e muyan
E) Iyan ree
  • 40. 39. Awon oro aropo oruko wo ni o wa ninu gbolohun yii? "Mo ti ri won tipetipe"
A) Ri ati tipeipe
B) Won ati tipetipe
C) Mo ati won
D) Ri ati won
E) Mo ati ti
  • 41. 40. Ewo ni o lee sise oluwa, abo ati eyan ninu awon isori oro wonyii? Oro
A) Atokun
B) Asopo
C) Ise
D) Aropo oruko
E) Oruko
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.