Yoruba : 3rd Term Revision Questions: JSS2
  • 1. 1. 1100 ni onka Yoruba ni
A) Egberun
B) Egberin
C) Eedegbeta
D) Eedegbefa
E) Edegberin
  • 2. 2. Egbewa ni Figo je....
A) 2000
B) 3000
C) 6000
D) 4000
E) 5000
  • 3. 3. Orisii Oro ti a n lo ninu gbolohun ni a n pe ni ........
A) Oro edan
B) Ege Oro
C) Isori Oro
D) Oro gbolohun
E) Ede Oro
  • 4. 4. Oro ise ni ede geesi ni ...
A) Syllable
B) Sound application
C) Paragraph
D) Verb
E) Alphabet
  • 5. 5. Melo ni isori Oro ti a ni ninu ede Yoruba? .
A) Mewa
B) Mejo
C) Ogbon
D) Ogun
E) Mesan
  • 6. 6. ....... Je afo ti a fi ohun to dun gbe Jade, ti o so dun leti lati gbo
A) Ilu
B) Orin
C) Ibile
D) Ofo
E) Isare
  • 7. 7. Ewo ni orin Ibile ninu awon wonyii? Orin
A) Eebu
B) Igbeyawo
C) Ose
D) Ikokuko
E) Epe
  • 8. 8. Irufe Orin to awon omode maa n ko ti won ba n sere ni Orin....
A) Epe sise
B) Ekun iyawo
C) Orin eebu
D) Esu pipe
E) Eremode
  • 9. 9. Orin " Boju Boju " ni asiko osupa he apeere Orin
A) Eremode
B) Oosa
C) Ebo
D) Ayeye
E) Ifa
  • 10. 10. Irufe Orin to awon osise maa n ko ni enu ise ni Orin
A) Eebu
B) Amuseya
C) Oosa
D) Eremode
E) Igbeyawo
  • 11. 11. Orisi isaare melo ni o wa ninu ede Yoruba?
A) Mefa
B) Meta
C) Meji
D) Marun
E) Merin
  • 12. 12. Ewo ninu awon wonyii ni apeere isare ajemesin?
A) Apepe
B) Iyere ifa
C) Eti yeri
D) Bolojo
E) Ekun iyawo
  • 13. 13. Awon ohun pipe ti a n lo nibi ayeye ni isere....
A) Ajemayeye
B) Ajemere
C) Ajemeko
D) Ajemese
E) Ajemesin
  • 14. 14. Orisii Alo to ko ni orin ninu no a n pe ni Alo....
A) Apaso
B) Apami
C) Apamo
D) Apaje
E) Apagbe
  • 15. 15. Aalo ti o ni orin ninu ni aalo
A) Apagbo
B) Apamo
C) Apagbe
D) Apaso
E) Apari
  • 16. 16. Ona esin ti Yoruba n gba sin Olorun ni Ilana abalaye ni esin.....
A) Atijo
B) Alejo
C) Gbajumo
D) Ibile
E) Tileyii
  • 17. 17. Esin see Pataki ni awujo Yoruba nitori pe esin
A) n ko wa lole
B) n ko wa ni iwa jagidijagan
C) n je ki a maa ri agbalagba fin
D) n je ki a maa paro
E) n ko wa ni iwa ti Olorun fe
  • 18. 18. Ewo ni kii se oruko Olodumare ninu awon wonyii?
A) Olorun
B) Elepeyo
C) Elemii
D) Obarisa
E) Eleda
  • 19. 19. Lati fi ipo Olodumare han , awon Yoruba tun maa Olorun o ba bayii, ayafi
A) Apata ayeraye
B) Atoobajaye
C) Ogbagba tii--gba-alailara
D) Esu kukuru
E) Olowo gbogboro
  • 20. 20. Ewo ni kii se esin ode-oni ninu awon wonyii? Esin
A) Abalaye
B) Kirisiteni
C) Ekenka
D) Musulumi
E) Buda
  • 21. 21. Ija esin kii waye laarin awon Yoruba nitori pe, won gbagbo pe, esin ko faja,
A) Orisa ni awon yoo maa sin
B) Ife ni Olorun
C) Jagidijagan ni o daa
D) Aje ni won mo
E) Epe ni won yoo fi lole
  • 22. 24. Ara ose to ija esin maa n da sile ninu ilu ni pe, o maa
A) n tu ilu ni
B) bi ore si aarin awon eniyan
C) n tun ona ilu se
D) je ku ounje maa po sii ninu ilu
E) je ki awon ero maa po sii ninu ilu
  • 23. 25. Ewo ni kii se ohun eelo ogun ninu awon n kan wonyii?
A) Oko
B) Kondo
C) Ofa
D) Obe
E) Ounje
  • 24. 26. Ewo ninu awon n kan wonyii ni ko so ninu ohun eelo isomoloruko ?
A) Eja
B) Elubo
C) Iru
D) Epo
E) Eku
  • 25. 27. Ni ile Yoruba, ojo kelo ni a maa n so awon ibeji loruko? Ojo
A) Kejo
B) Kefa
C) Keje
D) Kesan
E) Kewa
  • 26. 28. Ona melo ni litireso apileko pin si?
A) Meje
B) Marun
C) Merin
D) Mefa
E) Meta
  • 27. 29. Litireso ti a kii ko sile, sugbon ti o je pe Inu opolo ni won ti maa n soo Jade ni litireso
A) Apetunpe
B) Awitunwi
C) Alohuun
D) Apeko
E) Apileko
  • 28. 28. Eni ti o ko iwe litireso fun kika awon eniyan lati ka ni a n pe ni
A) Olusewe
B) Akowe
C) Oniwe
D) Onkowe
E) Olukawe
  • 29. 29. "Oruko omo ni ijanu omo" fi han , Pataki
A) Bibimo
B) Omo tito
C) Orin kiko fun omo
D) Isomoloruko
E) Omo bibi
  • 30. 30. Ewo ninu awon gbolohun wonyii ni ko si ninu eto isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Fifi ohun eelo isomoloruko wure
B) Fifun omo lowo
C) Jiju omo sodo
D) Fifi ara omo gbe ekan omi Ori orule
E) Fifun omo loruko
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.