Ede Yoruba Jss1:2nd term Exam
  • 1. 1. Awon Omo __________ ni won ma n je oba kaakiri Ile Yoruba
A) Arugbo
B) Oduduwa
C) Asesebi
D) Oke okun
  • 2. 2. Oriki oba ni " ki Ade o pe _______
A) Nidi
B) Lorun
C) Lese
D) Lori
  • 3. 3 _______ ni oruko oye oba abalabi
A) Alabalabi
B) Onijero
C) Oluwo
D) Jagunjagun
  • 4. 4. "Olu "ni oruko oye ti won je ni _________
A) Osogbo
B) Ilaro
C) Lagos
D) Ibadan
  • 5. 5. Ninu ewi 'Ore rere' ore relarela ki pe e
A) Bimo
B) Ga
C) Mo iwe
D) Reja
  • 6. 6. Ore rerunrerun kii pe
A) Lowo
B) Ra moto
C) Pupa
D) sera won nibi
  • 7. 7. Aroko ni
A) Ohun ti o ni emi
B) Ohun to a ko ni Fe si
C) Ohun ti o ga ju
D) Ohun to a ro lokan to a si ko
  • 8. 8. ...... ni ege oro ti eemi lee gbe jade leekan soso
A) Ewi
B) Silebu
C) Ase
D) Orin
  • 9. 9. Kin ni ami ihun oro yii KF duro fun?
A) Konsonanti + iro ohun
B) Konsonanti + Silebu
C) Konsonanti + Faweeli
D) Konsonanti + ede
E) Konsonanti + Akoto
  • 10. 10. Pin oro yii si Silebu - igbale
A) Igb - a- le
B) Igba - le
C) Igbal -e
D) I- gba - le
E) Ig - ba - le
  • 11. 11. Silebu melo ni oro yii ni - agbalagba ?
A) Meje
B) Meta
C) Mefa
D) Marun
E) Merin
  • 12. 12. Pin oro yii si silebu - Alabahun
A) A -laba- hun
B) A- la -bah -un
C) Al-a- ba -hu -n
D) A -la -ba - hun
E) Al -a -ba -hun
  • 13. 13. Ohun akoko ti a ni lati ko ti a ba n ko aroko ni
A) Ikadi
B) Ifaara
C) Ilapa ero
D) Akole
E) Ipin afo
  • 14. 14. Introduction ni a n pe ni ....... ninu aroko Yoruba
A) Ifaara
B) Akole
C) Ifihan
D) Ikadi
E) Ero okan
  • 15. 15. Topic ninu aroko Yoruba ni.....
A) Ifaara
B) Ilapa ero
C) Aroko
D) Ipin afo
E) Akole
  • 16. 16. ..... ni o toka isele inu aroko
A) Ipin afo
B) Ifaara
C) Akole
D) Ikadi
E) Koko oro
  • 17. 17. Ki ni o maa n tele akole ti a ba n ko aroko oniroyin?
A) Koko oro
B) Atako oro
C) Ifaara
D) Ikadi
E) Awawi
  • 18. 18. Ohun ti a n ko aroko le lori ni......
A) Iwadi
B) Koko oro
C) Ifaara
D) Akole
E) Ikadi
  • 19. 19. Aroko oniroyin je iroyin ohun ti
A) a ko mo
B) ti o je iro
C) ti ko sele
D) ti yoo sele lola
E) o sele loju wa
  • 20. 20. Apeere aroko oniroyin nii __
A) Ile eja kan ti o jona
B) Ibeere
C) Bi mo se Fe lo isimin ti o n bo lona
D) Iresi data ju eba lo lowuro
E) Iwulo agbado data ju paki lo
  • 21. 21. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun yii? Ade je pofupoofu
A) Pofupoofu
B) Ade
C) Je
D) Si
E) Pofu
  • 22. 22. Silebu melo ni o wa ninu oro yii- pofupoofu
A) Mefa
B) Meta
C) Meje
D) Marun
E) Merin
  • 23. 23. Ilapa ero tumo si
A) Conclusion
B) Introduction
C) Outline of points
D) Topic
E) Paragraph
  • 24. 24. Akaye ni
A) Ayoka ti a ka ti o ye ni yekeyeke
B) Ala oju orun
C) Ayoka ti o daru
D) Oro siso
  • 25. 25. Ki akaye Le ye ni
A) Ki a ka smoke laala
B) A gbodo kaa bi Eemeji
C) Ki aka nigba ogun
D) FKF
E) A ko gbodo kaa rara
  • 26. 26. E wo ni Kii see Ihun silebu
A) F
B) KFNKF
C) KK
D) KF
  • 27. 27. Gbangba je
A) Kfnkf
B) NKfKf
C) FFKFN
D) KfkfN
  • 28. 28 Silebu me lo ni ijakadi
A) Mefa
B) Meji
C) Merin
D) Meta
  • 29. 29.Ninu ewi"iwa ole" iwa ole
A) Mu ni lowo
B) Mu ni rewa
C) Kii se Iwa to ni laari
D) Gbe ni de bi gi ga
  • 30. 30. Ole fi Ile aye se
A) Digereu lasan ni
B) Lore
C) Faari
D) Lowo
E) Kole
  • 31. 31. Pin oro yii si silebu "Alangba"
A) A -la -n -g -b -a
B) Al -a -n -gb -a
C) A -la -(n) -gba
D) A -lan -gba
E) Alan -gba
  • 32. 32.Eya Ara ifo ni
A) Eya Ara tio mo fonifoni
B) Eya Ara to o side papo ti o so gbe iro ede jade ninu enu
C) Eya Ara to o ba iro ede je
D) Eya Ara to o doti
  • 33. 33. Eya Ara ifo pin so orisii ona
A) Meji
B) Igba
C) Ogun
D) Mejo
  • 34. 34. Eya Ara ifo ti a Le fi oju ri ni
A) Ahon
B) Tanaa onafun
C) Olele
D) Afase
  • 35. 35. Eya Ara ifo ti a Ko Le fi oju ri ni
A) Ahon
B) Imu
C) Eyin
D) Edo foro
  • 36. 37. Ewo ni eya ara ifo ?
A) Ese
B) Eti
C) Apa
D) Inu gogongo
E) Agbon
  • 37. 38. 141 ni
A) Ookanlelogoje
B) Merinlelokan
C) Ookanlemerin
D) Okanatimerin
  • 38. 39.ayeye ojo ibi mi je aroko
A) Isorongbesi
B) Alariyanjiyan
C) Alayojuran
D) Oniroyin
  • 39. 40. 150 ni onka Yoruba je
A) Aadofa
B) Aadoje
C) Aadojo
D) Ogoje
E) Ogojo
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where a math practice test is always one click away.