AIC Yoruba JSS 2 1st term exam 2024
  • 1. 1. Kínní orukọ iwe litiresọ tẹka nínú kilaasi
A) Ẹbun iyebiye
B) Ẹkùn ale
C) Odaju
D) Obìnrin atata
  • 2. 2. Fawẹẹli aranmupe jẹ melo
A) Meta
B) Marun
C) Meji
D) Mẹrin
  • 3. 3. Ìsòrí ọrọ yoruba jẹ melo
A) Mokanla
B) Mejo
C) Mejila
D) Mewa
  • 4. 4. ...... Ni awọn ọrọ ti a n lo dipo ọrọ orukọ nínú gbólóhùn
A) Ọrọ ẹyàn
B) Ọrọ ise
C) Ọrọ atọkun
D) Ọrọ arọpo orukọ
  • 5. 5. Irú àrùn wo ni akewi sọ pe Sawyer kọ wọlu(nínú ìwe litiresọ)
A) Jẹjẹrẹ
B) Jẹfun jẹfun
C) Jẹdọjẹdọ
D) Ẹbola
  • 6. 6. Bawo ni yoruba se ma n ki AWAKỌ
A) Awaye ọkọ oo
B) Asogun aaro
C) Ekaalẹ ooo
D) Arinpa ogun
  • 7. 7. Bawo ni yoruba se ma n ki ỌDẸ
A) Asogun aaro
B) Igba aaro
C) Arinpa ogun oo
D) Awaye ọkọ oo
  • 8. 8. Bawo ni yoruba se ma n ki ẸNI TÍ O BÁ BI ỌMỌ
A) Ẹku ọwọ lomi
B) EKu ikole
C) Arinpa ogun
D) Ẹku ọmọ bíbí
  • 9. 9. ..... Irú owò wo ni Tinubu n se (nínú ìwe litiresọ)
A) Owo worobo
B) Owo agbẹ
C) Owo ẹrú
D) Isẹ oluselu
  • 10. 10. Lara awọn ilana tose pataki fún àròsọ alapejuwe ni
A) Pipariwo soke
B) Yiyan ori ọrọ
C) Nifẹ alapejuwe
D) Sísọ ọrọ to ni ìtumọ
  • 11. 11. Ọdún wo ni efunroye Tinubu faye silẹ (nínú ìwe litiresọ)
A) 1886
B) 1997
C) 1888
D) 1887
  • 12. 12. ọjọ wo ni ọjọgbọn Dọra Akuyili faye silẹ (nínú ìwe litiresọ)
A) Ọjọ kẹjọ osu belu
B) Ọjọ keje oṣù ọpẹ
C) Ọjọ keje oṣù okudu
D) Ọjọ kẹjọ osu okudu
  • 13. 13. Ọjọ mélòó lo wa nínú ọsẹ
A) Mewa
B) Meje
C) Mesan
D) Mẹfa
  • 14. 14. Kínní orukọ ẹni tí o kọ arun ẹbola wọ Naijiria (nínú ìwe litiresọ)
A) Efunroye Tinubu
B) Patrick sawyer
C) Dọra Akuyili
D) Funmilayo kuti
  • 15. 15. 119 ni onka yoruba jẹ
A) Ookanlelọgọta
B) Aadọwa
C) Ààrùn leladota
D) Ookandinlọgọta
  • 16. 16. 180 ni onka yoruba jẹ
A) Ọgọwa
B) Aadọsan
C) Aadọwa
D) Ọgọsan
  • 17. 17. Nínú onka yoruba 200 lẹ jẹ ÌGBÀ tabi.........
A) Ọgọsan
B) Aadọwa
C) Ọgọwa
D) Aadọsan
  • 18. 18. Gbolohun ti a ba fi oju ìhun wo Pin Si ọna.......
A) Mẹta
B) Marun
C) Mẹrin
D) Meji
  • 19. 19. Irú ẹda wo ni funmilayọ kuti jẹ ( nínú ìwe litiresọ)
A) Obinrin oroju
B) Obìnrin takuntakun
C) Obìnrin alagbara
D) Obìnrin ọlẹ
  • 20. 20. Awọn melo ni wọn kọ ìwe litiresọ tẹ n kà nínú kilaasi
A) Mẹta
B) Mẹrin
C) Marun
D) Meji
  • 21. 21. Osù kinni nínú ọdún jẹ........
A) Igbe
B) Sẹẹrẹ
C) Ọwawa
D) Erelu
  • 22. 22. .........ni gbólóhùn ti kò ni ju ọrọ ìse kan lọ
A) Onibeere
B) Ọlọpọ ọrọ ise
C) Alákànpo
D) Alabọde
  • 23. 23. Lara awọn ọrọ ìse to le daduro gẹgẹ bí gbólóhùn ni....
A) Kunle pọn omi
B) Mo dide
C) Mo jeun
D) Joko o
  • 24. 24. ........... Ni gbólóhùn ti a fi ọrọ asopọ so awọn gbolohun miran pọ di ẹyọkan
A) Onibon
B) Ọlọpọ ọrọ ise
C) Alabọde
D) Alakanpọ
  • 25. 25. Orukọ miran fún gbólóhùn ẹlẹyọ ọrọ ìse ni.......
A) Alabọde
B) Alapejuwe
C) Alakanpọ
D) Ọlọpọ ọrọ ìse
  • 26. 26. Lara awọn ìpín gbólóhùn ti a ba fi oju lilo tàbí ìse wo ni......
A) Ìbéèrè
B) Alakanpọ
C) Alabọde
D) Ọlọpọ ọrọ ise
  • 27. 27. Àpèjúwe gbólóhùn alabọde ni.....
A) Adukẹ sun
B) Shade ati bunmi jẹun
C) Lọla lọ Si eko, o Si ra iwe bọ
D) Mo jẹun bakanna mo sì mú omi
  • 28. 28. Gbólóhùn ibeere Ni ọna ti a n gba se ìbéèrè pẹlu lílo oríṣi àwọn ọrọ.........
A) Iyanu
B) Àmì idanu duro
C) Ibeere
D) Àmì idanimo
  • 29. 29. Àpẹẹrẹ gbólóhùn wo ni eleyi.....SE ADE WA?
A) Aṣẹ
B) Alaye
C) ìbéèrè
D) Iyisodi
  • 30. 30. ......... Ni gbólóhùn ti a fi n se iroyin bi nnkan ṣe rí fún ẹlòmíràn láti gbọ
A) Ibeere
B) Iyanu
C) Alaye
D) Iyisodi
  • 31. 31. ....... Ni gbólóhùn ti a fi n pàṣẹ fún ẹni tí a n ba sọrọ
A) Aṣẹ
B) Iyisodi
C) Iyanu
D) Ibeere
  • 32. 32. Lara awọn ọrọ ti a nlo fún gbólóhùn ìyísódì ni......
A) Mo
B) Bẹẹni
C) Rara
D) Kii
  • 33. 33.yii gbólóhùn yí padà ṣí gbólóhùn ayisodi.. ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN WA SI ILE IWE LANA..
A) ILE IWE TUNTUN KO SI AKẸẸKỌ LANA
B) AKẸKỌ TUNTUN ỌMỌ KO WA SI ILE IWE
C) WA SI ILE IWE LANA ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN
D) ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN KO WA SI ILE IWE LANA
  • 34. 34. Ọrọ towa ni ipò olúwa nínú gbólóhùn yìí SHADE GBA OLUKỌ LÉTÍ PẸLU IBINU
A) Ibinu
B) Olùkọ
C) Leti
D) Shade
  • 35. 35. Ọrọ to wa ni ipò abọ nínú gbólóhùn yìí. ỌGBẸNI ABDUL HAFEEZ NAA ỌMỌ AKẸKỌ KAN TAARA
A) Ogbeni
B) Taara
C) Hafeez
D) Ọmọ akẹkọ
  • 36. 36 . Ọrọ ìse inu gbólóhùn yìí ILE TUNTUN GA GOGORO
A) Gogoro
B) Ile
C) Tuntun
D) Ga
  • 37. 37. Àpẹẹrẹ gbólóhùn alalaye ni....
A) Jade sita
B) Ojo naa fẹ Wu oku ọlẹ
C) Tani o jale
D) Suraju kii ki eniyan
  • 38. 38. 100 ni onka yoruba jẹ
A) Ẹgbẹrun
B) Ọgọrun
C) Ọgọfa
D) Aadọrun
  • 39. 39. 178 ni onka yoruba jẹ
A) Eejilelaadoje
B) Aarundinladoje
C) Eejidinlaadọsan
D) Eejidinlọgọsan
  • 40. 39. ...... Ni akojọpọ ọrọ ìse ati isẹ ti o n jẹ níbikíbi ti o ba ti jeyo
A) Mofiimu
B) Gbólóhùn
C) Silebu
D) Alabode
  • 41. 40 . ......ni ege ọrọ ti èémí lẹ gbé jade lẹẹkan soso
A) Fonọ́lọ́jì
B) Mofiimu
C) Gbólóhùn
D) Silebu
Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.