AIC Yoruba JSS 2 3rd CA test 2024
  • 1. 1. Alifabẹẹti ede Yorùbá Pin Si ọna melo
A) Meta
B) Marun
C) Merin
D) Meji
  • 2. 2. Fawẹẹli aranmupe jẹ melo
A) Meta
B) Meji
C) Marun
D) Mẹrin
  • 3. 3. Ìsòrí ọrọ yoruba jẹ melo
A) Mejo
B) Mokanla
C) Mewa
D) Mejila
  • 4. 4. ...... Ni awọn ọrọ ti a n lo dipo ọrọ orukọ nínú gbólóhùn
A) Ọrọ atọkun
B) Ọrọ arọpo orukọ
C) Ọrọ ise
D) Ọrọ ẹyàn
  • 5. 5. Ìkíni ni ilẹ yoruba Pin Si ọna
A) Mẹta
B) Meji
C) Mẹrin
D) Marun
  • 6. 6. Bawo ni yoruba se ma n ki AWAKỌ
A) Arinpa ogun
B) Awaye ọkọ oo
C) Ekaalẹ ooo
D) Asogun aaro
  • 7. 7. Bawo ni yoruba se ma n ki ỌDẸ
A) Arinpa ogun oo
B) Awaye ọkọ oo
C) Asogun aaro
D) Igba aaro
  • 8. 8. Bawo ni yoruba se ma n ki ẸNI TÍ O BÁ BI ỌMỌ
A) EKu ikole
B) Ẹku ọmọ bíbí
C) Arinpa ogun
D) Ẹku ọwọ lomi
  • 9. 9. ..... Àròsọ to n se àpèjúwe ibikan ati nnkan yo sẹlẹ gẹgẹ bí a ṣe ríi gan an pẹlú ohun ẹnu
A) Àròsọ àríyànjiyàn
B) Àròsọ alapejuwe
C) Àròsọ oloselu
D) Àròsọ onitan
  • 10. 10. Lara awọn ilana tose pataki fún àròsọ alapejuwe ni
A) Yiyan ori ọrọ
B) Nifẹ alapejuwe
C) Sísọ ọrọ to ni ìtumọ
D) Pipariwo soke
  • 11. 11. Lara awọn oríṣi isẹ ile ni.....
A) Omi pipọn
B) Ẹnu fifọ
C) Iwe kikọ
D) Ounjẹ jijẹ
  • 12. 12. ..........ni kosi lara awọn isẹ ile
A) Ina dida
B) Ilẹ gbigba
C) Omi pipọn
D) Ẹnu fifọ
  • 13. 13. Ọjọ mélòó lo wa nínú ọsẹ
A) Meje
B) Mesan
C) Mẹfa
D) Mewa
  • 14. 14. Ọjọ Sátidé ni yoruba n pe ni
A) Ọjọbọ
B) Ọjọru
C) Àbámẹ́ta
D) Ẹtì
  • 15. 15. 119 ni onka yoruba jẹ
A) Ààrùn leladota
B) Ookanlelọgọta
C) Ookandinlọgọta
D) Aadọwa
  • 16. 16. 180 ni onka yoruba jẹ
A) Aadọsan
B) Ọgọwa
C) Ọgọsan
D) Aadọwa
  • 17. 17. Nínú onka yoruba 200 lẹ jẹ ÌGBÀ tabi.........
A) Aadọsan
B) Aadọwa
C) Ọgọwa
D) Ọgọsan
  • 18. 18. Gbolohun ti a ba fi oju ìhun wo Pin Si ọna.......
A) Mẹrin
B) Marun
C) Mẹta
D) Meji
  • 19. 19. Osù melo lo wa nínú ọdún kan
A) Mẹrinla
B) Mẹsan
C) Mejila
D) Mẹwa
  • 20. 20. Osù kọkànlá ni èdè yorúbá jẹ...
A) Ẹrẹna
B) Sẹẹrẹ
C) Belu
D) Ọpẹ
  • 21. 21. Osù kinni nínú ọdún jẹ........
A) Igbe
B) Sẹẹrẹ
C) Ọwawa
D) Erelu
  • 22. 22. .........ni gbólóhùn ti kò ni ju ọrọ ìse kan lọ
A) Alabọde
B) Onibeere
C) Ọlọpọ ọrọ ise
D) Alákànpo
  • 23. 23. Lara awọn ọrọ ìse to le daduro gẹgẹ bí gbólóhùn ni....
A) Mo dide
B) Kunle pọn omi
C) Mo jeun
D) Joko o
  • 24. 24. ........... Ni gbólóhùn ti a fi ọrọ asopọ so awọn gbolohun miran pọ di ẹyọkan
A) Alabọde
B) Alakanpọ
C) Ọlọpọ ọrọ ise
D) Onibon
  • 25. 25. Orukọ miran fún gbólóhùn ẹlẹyọ ọrọ ìse ni.......
A) Alabọde
B) Alakanpọ
C) Ọlọpọ ọrọ ìse
D) Alapejuwe
  • 26. 26. Lara awọn ìpín gbólóhùn ti a ba fi oju lilo tàbí ìse wo ni......
A) Ọlọpọ ọrọ ise
B) Ìbéèrè
C) Alabọde
D) Alakanpọ
  • 27. 27. Àpèjúwe gbólóhùn alabọde ni.....
A) Shade ati bunmi jẹun
B) Adukẹ sun
C) Mo jẹun bakanna mo sì mú omi
D) Lọla lọ Si eko, o Si ra iwe bọ
  • 28. 28. Gbólóhùn ibeere Ni ọna ti a n gba se ìbéèrè pẹlu lílo oríṣi àwọn ọrọ.........
A) Àmì idanimo
B) Iyanu
C) Àmì idanu duro
D) Ibeere
  • 29. 29. Àpẹẹrẹ gbólóhùn wo ni eleyi.....SE ADE WA?
A) Alaye
B) Iyisodi
C) Aṣẹ
D) ìbéèrè
  • 30. 30. ......... Ni gbólóhùn ti a fi n se iroyin bi nnkan ṣe rí fún ẹlòmíràn láti gbọ
A) Iyanu
B) Alaye
C) Iyisodi
D) Ibeere
  • 31. 31. ....... Ni gbólóhùn ti a fi n pàṣẹ fún ẹni tí a n ba sọrọ
A) Iyanu
B) Iyisodi
C) Ibeere
D) Aṣẹ
  • 32. 32. Lara awọn ọrọ ti a nlo fún gbólóhùn ìyísódì ni......
A) Kii
B) Bẹẹni
C) Rara
D) Mo
  • 33. 33.yii gbólóhùn yí padà ṣí gbólóhùn ayisodi.. ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN WA SI ILE IWE LANA..
A) AKẸKỌ TUNTUN ỌMỌ KO WA SI ILE IWE
B) ILE IWE TUNTUN KO SI AKẸẸKỌ LANA
C) WA SI ILE IWE LANA ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN
D) ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN KO WA SI ILE IWE LANA
  • 34. 34. Ọrọ towa ni ipò olúwa nínú gbólóhùn yìí SHADE GBA OLUKỌ LÉTÍ PẸLU IBINU
A) Olùkọ
B) Shade
C) Leti
D) Ibinu
  • 35. 35. Ọrọ to wa ni ipò abọ nínú gbólóhùn yìí. ỌGBẸNI ABDUL HAFEEZ NAA ỌMỌ AKẸKỌ KAN TAARA
A) Ogbeni
B) Ọmọ akẹkọ
C) Taara
D) Hafeez
  • 36. 36 . Ọrọ ìse inu gbólóhùn yìí ILE TUNTUN GA GOGORO
A) Ga
B) Ile
C) Gogoro
D) Tuntun
  • 37. 37. Àpẹẹrẹ gbólóhùn alalaye ni....
A) Suraju kii ki eniyan
B) Tani o jale
C) Jade sita
D) Ojo naa fẹ Wu oku ọlẹ
  • 38. 38. 100 ni onka yoruba jẹ
A) Ẹgbẹrun
B) Ọgọfa
C) Ọgọrun
D) Aadọrun
  • 39. 39. 178 ni onka yoruba jẹ
A) Eejilelaadoje
B) Eejidinlọgọsan
C) Eejidinlaadọsan
D) Aarundinladoje
  • 40. 39. ...... Ni akojọpọ ọrọ ìse ati isẹ ti o n jẹ níbikíbi ti o ba ti jeyo
A) Mofiimu
B) Gbólóhùn
C) Silebu
D) Alabode
  • 41. 40 . ......ni ege ọrọ ti èémí lẹ gbé jade lẹẹkan soso
A) Mofiimu
B) Silebu
C) Fonọ́lọ́jì
D) Gbólóhùn
Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.