AIC Yoruba JSS 2 1st term exam 2024
  • 1. 1. Kínní orukọ iwe litiresọ tẹka nínú kilaasi
A) Odaju
B) Obìnrin atata
C) Ẹkùn ale
D) Ẹbun iyebiye
  • 2. 2. Fawẹẹli aranmupe jẹ melo
A) Marun
B) Meji
C) Meta
D) Mẹrin
  • 3. 3. Ìsòrí ọrọ yoruba jẹ melo
A) Mejila
B) Mewa
C) Mokanla
D) Mejo
  • 4. 4. ...... Ni awọn ọrọ ti a n lo dipo ọrọ orukọ nínú gbólóhùn
A) Ọrọ ẹyàn
B) Ọrọ ise
C) Ọrọ atọkun
D) Ọrọ arọpo orukọ
  • 5. 5. Irú àrùn wo ni akewi sọ pe Sawyer kọ wọlu(nínú ìwe litiresọ)
A) Jẹjẹrẹ
B) Jẹfun jẹfun
C) Jẹdọjẹdọ
D) Ẹbola
  • 6. 6. Bawo ni yoruba se ma n ki AWAKỌ
A) Ekaalẹ ooo
B) Awaye ọkọ oo
C) Asogun aaro
D) Arinpa ogun
  • 7. 7. Bawo ni yoruba se ma n ki ỌDẸ
A) Igba aaro
B) Arinpa ogun oo
C) Awaye ọkọ oo
D) Asogun aaro
  • 8. 8. Bawo ni yoruba se ma n ki ẸNI TÍ O BÁ BI ỌMỌ
A) EKu ikole
B) Ẹku ọmọ bíbí
C) Arinpa ogun
D) Ẹku ọwọ lomi
  • 9. 9. ..... Irú owò wo ni Tinubu n se (nínú ìwe litiresọ)
A) Owo worobo
B) Owo agbẹ
C) Isẹ oluselu
D) Owo ẹrú
  • 10. 10. Lara awọn ilana tose pataki fún àròsọ alapejuwe ni
A) Yiyan ori ọrọ
B) Pipariwo soke
C) Nifẹ alapejuwe
D) Sísọ ọrọ to ni ìtumọ
  • 11. 11. Ọdún wo ni efunroye Tinubu faye silẹ (nínú ìwe litiresọ)
A) 1888
B) 1887
C) 1886
D) 1997
  • 12. 12. ọjọ wo ni ọjọgbọn Dọra Akuyili faye silẹ (nínú ìwe litiresọ)
A) Ọjọ keje oṣù ọpẹ
B) Ọjọ keje oṣù okudu
C) Ọjọ kẹjọ osu okudu
D) Ọjọ kẹjọ osu belu
  • 13. 13. Ọjọ mélòó lo wa nínú ọsẹ
A) Meje
B) Mẹfa
C) Mewa
D) Mesan
  • 14. 14. Kínní orukọ ẹni tí o kọ arun ẹbola wọ Naijiria (nínú ìwe litiresọ)
A) Dọra Akuyili
B) Efunroye Tinubu
C) Funmilayo kuti
D) Patrick sawyer
  • 15. 15. 119 ni onka yoruba jẹ
A) Ookanlelọgọta
B) Aadọwa
C) Ààrùn leladota
D) Ookandinlọgọta
  • 16. 16. 180 ni onka yoruba jẹ
A) Ọgọsan
B) Aadọsan
C) Aadọwa
D) Ọgọwa
  • 17. 17. Nínú onka yoruba 200 lẹ jẹ ÌGBÀ tabi.........
A) Ọgọwa
B) Ọgọsan
C) Aadọsan
D) Aadọwa
  • 18. 18. Gbolohun ti a ba fi oju ìhun wo Pin Si ọna.......
A) Mẹta
B) Meji
C) Mẹrin
D) Marun
  • 19. 19. Irú ẹda wo ni funmilayọ kuti jẹ ( nínú ìwe litiresọ)
A) Obìnrin takuntakun
B) Obìnrin alagbara
C) Obinrin oroju
D) Obìnrin ọlẹ
  • 20. 20. Awọn melo ni wọn kọ ìwe litiresọ tẹ n kà nínú kilaasi
A) Mẹrin
B) Marun
C) Mẹta
D) Meji
  • 21. 21. Osù kinni nínú ọdún jẹ........
A) Sẹẹrẹ
B) Igbe
C) Erelu
D) Ọwawa
  • 22. 22. .........ni gbólóhùn ti kò ni ju ọrọ ìse kan lọ
A) Alákànpo
B) Onibeere
C) Alabọde
D) Ọlọpọ ọrọ ise
  • 23. 23. Lara awọn ọrọ ìse to le daduro gẹgẹ bí gbólóhùn ni....
A) Mo jeun
B) Kunle pọn omi
C) Mo dide
D) Joko o
  • 24. 24. ........... Ni gbólóhùn ti a fi ọrọ asopọ so awọn gbolohun miran pọ di ẹyọkan
A) Ọlọpọ ọrọ ise
B) Onibon
C) Alabọde
D) Alakanpọ
  • 25. 25. Orukọ miran fún gbólóhùn ẹlẹyọ ọrọ ìse ni.......
A) Alapejuwe
B) Ọlọpọ ọrọ ìse
C) Alabọde
D) Alakanpọ
  • 26. 26. Lara awọn ìpín gbólóhùn ti a ba fi oju lilo tàbí ìse wo ni......
A) Ìbéèrè
B) Alakanpọ
C) Alabọde
D) Ọlọpọ ọrọ ise
  • 27. 27. Àpèjúwe gbólóhùn alabọde ni.....
A) Lọla lọ Si eko, o Si ra iwe bọ
B) Shade ati bunmi jẹun
C) Adukẹ sun
D) Mo jẹun bakanna mo sì mú omi
  • 28. 28. Gbólóhùn ibeere Ni ọna ti a n gba se ìbéèrè pẹlu lílo oríṣi àwọn ọrọ.........
A) Ibeere
B) Àmì idanimo
C) Àmì idanu duro
D) Iyanu
  • 29. 29. Àpẹẹrẹ gbólóhùn wo ni eleyi.....SE ADE WA?
A) ìbéèrè
B) Aṣẹ
C) Alaye
D) Iyisodi
  • 30. 30. ......... Ni gbólóhùn ti a fi n se iroyin bi nnkan ṣe rí fún ẹlòmíràn láti gbọ
A) Ibeere
B) Iyanu
C) Iyisodi
D) Alaye
  • 31. 31. ....... Ni gbólóhùn ti a fi n pàṣẹ fún ẹni tí a n ba sọrọ
A) Ibeere
B) Iyisodi
C) Iyanu
D) Aṣẹ
  • 32. 32. Lara awọn ọrọ ti a nlo fún gbólóhùn ìyísódì ni......
A) Kii
B) Bẹẹni
C) Mo
D) Rara
  • 33. 33.yii gbólóhùn yí padà ṣí gbólóhùn ayisodi.. ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN WA SI ILE IWE LANA..
A) AKẸKỌ TUNTUN ỌMỌ KO WA SI ILE IWE
B) ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN KO WA SI ILE IWE LANA
C) WA SI ILE IWE LANA ỌMỌ AKẸKỌ TUNTUN
D) ILE IWE TUNTUN KO SI AKẸẸKỌ LANA
  • 34. 34. Ọrọ towa ni ipò olúwa nínú gbólóhùn yìí SHADE GBA OLUKỌ LÉTÍ PẸLU IBINU
A) Shade
B) Ibinu
C) Olùkọ
D) Leti
  • 35. 35. Ọrọ to wa ni ipò abọ nínú gbólóhùn yìí. ỌGBẸNI ABDUL HAFEEZ NAA ỌMỌ AKẸKỌ KAN TAARA
A) Taara
B) Hafeez
C) Ogbeni
D) Ọmọ akẹkọ
  • 36. 36 . Ọrọ ìse inu gbólóhùn yìí ILE TUNTUN GA GOGORO
A) Ile
B) Ga
C) Tuntun
D) Gogoro
  • 37. 37. Àpẹẹrẹ gbólóhùn alalaye ni....
A) Jade sita
B) Suraju kii ki eniyan
C) Tani o jale
D) Ojo naa fẹ Wu oku ọlẹ
  • 38. 38. 100 ni onka yoruba jẹ
A) Aadọrun
B) Ọgọfa
C) Ọgọrun
D) Ẹgbẹrun
  • 39. 39. 178 ni onka yoruba jẹ
A) Aarundinladoje
B) Eejilelaadoje
C) Eejidinlọgọsan
D) Eejidinlaadọsan
  • 40. 39. ...... Ni akojọpọ ọrọ ìse ati isẹ ti o n jẹ níbikíbi ti o ba ti jeyo
A) Mofiimu
B) Gbólóhùn
C) Silebu
D) Alabode
  • 41. 40 . ......ni ege ọrọ ti èémí lẹ gbé jade lẹẹkan soso
A) Silebu
B) Mofiimu
C) Fonọ́lọ́jì
D) Gbólóhùn
Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.