Yoruba JSS 3 3rd CA test 2024
  • 1. 1. Isori oro melo ni a ni ninu ede Yoruba?
A) Mẹta
B) Meje
C) Mẹfa
D) Mejo
  • 2. 2. Ewo ni isori oro ti o n toka isele ninu gbolohun? Oro
A) Oruko
B) Ise
C) Aponle
D) Asopo
  • 3. 3. ....... jẹ ọkan lára awọn abala ìhun gbólóhùn ede yoruba
A) Mofiimu
B) Apola
C) Silebu
D) Ọrọ orukọ
  • 4. 4. Lara awọn iṣọri ọrọ ti àtòjọ láti hun gbólóhùn ede Yorùbá ni........
A) Silebu
B) Fonọ́lọ́jì
C) Ọrọ ise
D) Mofiimu
  • 5. 5. Àpólà inú ede yoruba jẹ melo
A) Mẹta
B) Marun
C) Meji
D) Merin
  • 6. 6. Lara awọn oríṣi Iro kọnsonanti ni awọn wọnyi ayafi.........
A) Kọnsonanti akunyun
B) Kọnsonanti aikunyun
C) Kọnsonanti aranmupe
D) Konsonanti ayinmupe
  • 7. 7. ......... Lo jẹmọ́ ètò Iro ede Yorùbá ati bí a ṣe n lo Iro ede Yorùbá
A) Gbólóhùn
B) Fonọ́lọ́jì
C) Silebu
D) Mofiimu
  • 8. 8. ......... Ni Iro ti a gbé jade nígbàtí idiwọ wá fún eemi
A) Silebu
B) Mofiimu
C) Kọnsonanti
D) Fawẹẹli
  • 9. 9. ....... Ni ọna ti a n Gba pa ìró jẹ nínú ọrọ tabi àpólà laiyan pipa Iro fawẹẹli tàbí kọnsonanti jẹ nínú ọrọ
A) Mofiimu
B) Silebu
C) Isunki
D) Gbólóhùn
  • 10. 10. Lara awọn àpẹẹrẹ isunki ni.....
A) Oluwa
B) Ile iwe
C) Olodumare
D) Adua
  • 11. 11. Gbólóhùn ọrọ LAYELAYE yóò di.........ti a ba pa ìró jẹ
A) Lailai
B) Laylay
C) Laelae
D) Layeelayee
  • 12. 12. ........ Ni ohun ini ẹni tí o ku, eyi tọka si dukia bíi ilẹ,oko owó ẹrú ati awọn nkán miran
A) Inawo
B) Ogun
C) Ọrọ sisọ
D) Isinku
  • 13. 13. Ọna melo ni yorúbá ma n Gba Pin ogun
A) Mẹta
B) Meji
C) Marun
D) Mẹrin
  • 14. 14. Gbogbo kọnsonanti ede Yorùbá jẹ́.......
A) Mejilelogun
B) Mejidinlogun
C) Ogun
D) Mẹtala
  • 15. 15. .......... Ni pínpín ogun Si iye ọmọ ti oku bi
A) Ìdí igi
B) Dọgbadọgba
C) Olorijori
D) Ilana ofin islam
  • 16. 16. Lara awọn ìsọ ọrọ èdè yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Ọrọ òwe
B) Ọrọ apọnle
C) Ọrọ atọkun
D) Ọrọ asopọ
  • 17. 17. Lara awọn àpólà inú ede yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Àpólà apọnle
B) Àpólà ọrọ ìse
C) Àpólà ọrọ orukọ
D) Àpólà asopọ
  • 18. 18. Nínú ìwe litiresọ ta ká ni ni kilaasi.... orukọ iwe náà ni.......
A) Iwa ika
B) Ololufẹ
C) Isẹ Aje
D) Ọdaju
  • 19. 19.. orukọ ẹni tokọ iwe náà ni.....
A) Bọsẹde iroko ọbaniyi
B) Olaleye Rukayat
C) Wasiu Akinpelu
D) Adewoyin Sunday
  • 20. 20. Ninu iwe litireso, ọkọ adéọlá jẹ.....
A) Omoluabi
B) Alaanu
C) Òní inure
D) Eyan buruku
  • 21. 21. Nínú ìwe litiresọ, iwe ẹri melo ni adéọlá ni
A) Marun
B) Mẹta
C) Mẹrin
D) Meji
  • 22. 22. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ ìlú wo ni adéọlá jẹ
A) Okeho
B) Aha
C) Òyó
D) Eko
  • 23. 23. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ melo ni adéọlá bi
A) Meji
B) Marun
C) Meje
D) Mẹfa
  • 24. 24. ....... Ni ege ọrọ ti okere julọ ti ale fi eemi ẹnu wà pẹ lẹẹkan soso
A) Fonọ́lọ́jì
B) Àmì ohun
C) Silebu
D) Mofiimu
  • 25. 25. Ọna melo ni a lè gbà hun silebu
A) Mẹrin
B) Meji
C) Marun
D) Mẹta
  • 26. 26. Àmì ohun melo ni o wa nínú èdè yorúbá
A) Mẹta
B) Meji
C) Marun
D) Mẹrin
  • 27. 27. Iro melo ni o se pàtàkì nínú èdè yorúbá
A) Mẹta
B) Meji
C) Marun
D) Mẹrin
  • 28. 28. Àpẹẹrẹ kọnsonanti aranmupe asesilebu ni....
A) Agbalumọ
B) Orombo
C) Osan
D) Isu
  • 29. 29.Ami ohun melo ni AJANLEKOKO ni
A) Mẹrin
B) Meje
C) Marun
D) Mẹfa
  • 30. 30. Amin ohun tí owa nínú IGBA(GARDEN EGG) ni
A) Do Mi
B) Re Re
C) Mi Do
D) Do Re
  • 31. 31. Amin ohun tí o wa nínú IGBA (200) ni
A) Re Mi
B) Do Re
C) Mi Mi
D) Re Re
  • 32. 32. Amin ohun tí o wa nínú IGBA(CALABASH) ni
A) Re Mi
B) Do Mi
C) Re Do
D) Re Re
  • 33. 33. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (HUSBAND)
A) Do Re
B) Mi Re
C) Re Do
D) Re Re
  • 34. 34. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (hoe) ni
A) Do Mi
B) Mi Do
C) Re Mi
D) Re Do
  • 35. 35. Nínú ìwe Lítíréṣọ̀, isẹ wo ni adéọlá n se koto rí isẹ ìjọba
A) Isẹ Irun didi
B) Káràkátà
C) Isẹ ole jija
D) Olùkọ
  • 36. 36. Silebu melo ni ọrọ yìí ni "ỌLỌRUNKẸMI"
A) Meje
B) Mẹrin
C) Marun
D) Mẹfa
  • 37. 37. Àmì ohun to wa nínú ọrọ YORUBA ni
A) Do Mi Re
B) Do Re Mi
C) Re Do Mi
D) Re mi Do
  • 38. 38. Lara awọn oríṣi oku abami ni awọn wọnyi ayafi........
A) Abuke
B) Adẹtẹ
C) Ẹni tí Sàngó pa
D) Arẹwa
  • 39. 39. Oríṣi oku melo lowa ni ilẹ yoruba
A) Marun
B) Meji
C) Mẹta
D) Mẹrin
  • 40. 40. Lara awọn wahala to ropọ mọ ogun pínpín ni ilẹ yoruba ni awọn wọnyi ayafi.......
A) Owu jijẹ
B) Gbigbe ara ẹni lọsí ile ẹjọ
C) Ija laarin ọbakan
D) Ini ifẹ ara ẹni
Created with That Quiz — where a math practice test is always one click away.