Ede Yoruba 3rd Term Revision Questions JSS1
  • 1. 1. Konsonanti wo ni ko so ninu ede Yoruba
A) K
B) T
C) Q
D) L
E) S
  • 2. 2. 540 ni onka Yoruba je
A) Oji le leedegbeta
B) Okoo le leedegbeta
C) Orin le legberin
D) Egberin
E) ota le legberin
  • 3. 3 .......,............. ni awon iwe ewi, itan aroso tabi ere onitan to onkowe ko sile kun kika
A) Litireso afogbon ko
B) Litireso apileko
C) Litireso amoomoko
D) Litireso alohun
  • 4. 4. Isori melo ni litireso apileko pin si?
A) Marun
B) Meji
C) Meta
D) Merin
E) Meje
  • 5. 5. Tani baba Oduduwa?
A) Buraimo
B) Oranmiyan
C) Lamurudu
D) Setiyu
E) Okanbi
  • 6. 6. Odun wo ni ede Yoruba do Kiko sile
A) 1845
B) 1843
C) 1844
D) 1842
E) 1846
  • 7. 7. Tani o tumo bibeli ede oyinbo si ede Yoruba?
A) Bonfrere joe
B) Ajayi crowther
C) Samuel Ajibode
D) Ajayi Simon
E) Adelabu Josef
  • 8. 8. Ilu wo ni won ti bi Alufa Samuel Ajayi Crowther
A) Ibadan
B) Owo
C) Saro
D) Osoogun
E) Ondo
  • 9. 9. Oroko so no awon oyinbo Koko n pe awon Yoruba
A) Osan
B) Aku
C) Eye
D) Efun
E) Eyo
  • 10. 10. Kinni ami ohun isale
A) So
B) La
C) Fa
D) Mi
E) Mi
  • 11. 11. Ohun akoko lati ko to a ba n ko aroko ni.....
A) Ifaara
B) Ikadi
C) Akole
D) Ipin afo
E) Ilapa ero
  • 12. 12. Kinni igbese akoko ninu let's Kiko ni.....
A) Adiresi
B) Ikadi
C) Deeti
D) Ori leta
E) Ifaara
  • 13. 13. Leta gbefe ni Leta to a ko si ...
A) Oga ile ifowo pamo
B) Olori ise oba
C) Oga ile ise
D) Egbon
E) Alaga ijoba ibile
  • 14. 14. Ojo melo ni Oduduwa ati awon eniyan re fi rin lati meka de ile Ife?
A) Aadowa ojo
B) Aadorun ojo
C) Aadata ojo
D) Aadorin ojo
E) Aadosan ojo
  • 15. 15. Ilu wo ni gbogbo omo Yoruba gba gege bii ororun won?
A) Ilu Sudan
B) Ilu Ondo
C) Ile Saro
D) Ilu Meka
E) Ile Ife
  • 16. 16. Ibo ni deeti ma n wa nini leta kiko? Abe........
A) Oruko akoleta
B) Ikadi
C) Ikini
D) Adiresi akoleta
E) Koko oro
  • 17. 17. Iru leta wo ni kii ni akole? Leta
A) Aroso
B) Isorongbesi
C) Gbefe
D) Akaye
E) Aigbefe
  • 18. 18. Silebu melo ni o wa ninu iranlowo?
A) Màrun
B) Merin
C) Meji
D) Mefa
E) Meta
  • 19. 19. Ewo kii se oro onisilebu kan ninu awon oro wonyii ?
A) Wa
B) Sa
C) Han
D) Ipin
E) Lo
  • 20. 20. Ipnle ti a ko ti lee ri eya Yoruba ni
A) Binni
B) Jos
C) Kwara
D) Ogun
E) Ondo
  • 21. 21. Oruko Oye oba Saki ni
A) Osamawe
B) Obara
C) Onjo
D) Alaafin
E) Okere
  • 22. 22. ......... ni Ilori awon eniyan to Oduduwa ba ni ile-ife
A) Buraimo
B) Agbonmiregun
C) Setiyu
D) Lamurudu
E) Alakija
  • 23. 23. Abikeyin Okanbi ni
A) Orunmila
B) Oranmiyan
C) Osun
D) Ogun
E) Oràngun
  • 24. 24. Tani akobi Oduduwa
A) Onibon
B) Odede
C) Olowu
D) Olupopo
E) Oni Sabe
  • 25. 25. Ewo ninu omo Oduduwa ni o lowo ju?
A) Alakija
B) Oranmiyan
C) Okanbi
D) Alaketu
E) Alake
  • 26. 26. Okoo le leedegberin
A) 1380
B) 940
C) 820
D) 720
E) 1530
  • 27. 27. Ara abuda to a maa n wo ti a ba n kawe litireso apileko niwonyii, ayafi
A) Eda ati ifiwaweda
B) Ebi onkowe
C) Ibudo itan
D) Koko oro Inu itan
E) Ahunpo itan
  • 28. 28. Eni ti o ko leta ni a n pe ni
A) Akoleta
B) Amuleta
C) Oniwe
D) Akowe
E) Oluko
  • 29. 29. Ewo ninu awon omo Oduduwa ni o jogun ileke ?
A) Alaketu
B) Olupopo
C) Olowu
D) Onisabe
E) Oràngun
  • 30. 30. Tani Ooni akoko ni ile-ife?
A) Agbonmiregun
B) Gogobiri
C) Kukawa
D) Lamurudu
E) Oduduwa
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.