- 1. 1. Melo ni gbogbo alifabeeti ede Yoruba?
A) Meedogbon B) Mokanlelogun C) Meedogun
- 2. 2. Okoo leerugba je .......ni figo
A) 420 B) 220 C) 320
- 3. 3. 106 ni onka Yoruba je
A) Eerin din legbeta B) Eerin din laadofa C) Eerin din loodun
- 4. 4. Odun wo no ede Yoruba koko di koko sile?
A) 1892 B) 1872 C) 1842
- 5. 5. Tani o tumo Bibeli ede oyinbo si ede Yoruba?
A) Samuel Ajayi Crowder B) J .P Odunjo C) Obafemi Awoloo
- 6. 6. Ewo no o ba akoto ode oni my ninu awon won yii?
A) Aiye B) Laelae C) Shaki
- 7. 7. Bawo ni o to ki a ko gbolohun yii-"biotilejepe" ni akoto ode oni?
A) Bio tile jepe B) Bi o tile je pe C) Bi o tileje pe
- 8. 8. Silebu melo lo wa ninu Oro yii"oloore"?
A) Merin B) Marun C) Meta
- 9. 9. Ewo ninu awon oro won yii ni oro onisilebu kan?
A) Gba B) Omi C) Inu
- 10. 10. Kini ohun a o koko ko , ti a ba fe ko aroko alapejuwe ?
A) Akole B) Oruko C) Ifaara
- 11. 11. Apeere akole fun aroko oniroyin ni
A) Eto idibo to koja B) Igi owo C) Iya mi
- 12. 12. Ewo ni igbese akoko ninu leta kiko? Kiko....
A) Oruko akoleta B) Deeti C) Adiresi
- 13. 13. Leta ti a maa n ko lati fi wa ise ni leta......
A) Aigbefe B) Gbefe C) Onise
- 14. 14. Egberun ni onka Yoruba je
A) 1000 B) 2000 C) 500
- 15. 15. 150 ni ...... ni onka Yoruba
A) Aadota B) Ogoji C) Aadojo
- 16. 16. Tani o wa laarin oko ati iyawo ki won to fe Ara won?
A) Mama oko B) Baba iyawo C) Alarina
- 17. 17. Eru to oko maa ko lo sile iyawo ki o to fee ni a n pe ni.....
A) Idana B) Iyawo C) Saraa
- 18. 18. Tani o je ade-ori fun iyawo?
A) Baba re B) Oko re C) Iya re
- 19. 19. Traditional marriage ni Yoruba n pe ni igbeyawo
A) Soosi B) Mosalaasi C) Ibile
- 20. 20. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun yii?"Kola lu mi"
A) Kola B) Lu C) Mi
|