- 1. 1. Nínú ìwe alawiiye, (akọle : ogun idanwo)tani o mu awọn ọmọ lọ sì ile onisegun
A) Bọla B) Dupẹ C) Ẹgbọn bọsẹ D) Bọsẹ
- 2. 2. Nínú akole ogun idanwo ìwe alawiiye...awọn wo ni wón ro pe awọn yóò gbà gbogbo maaki tan
A) Bọsẹ ati dupẹ B) Ẹgbọn Bola C) Bola D) Tolani
- 3. 3.ninu iwe alawiiye akọle ogun idanwo..Ta ni kogba pe ogun idanwo n bẹ
A) Dupẹ B) Bọla C) Ṣeṣan D) Ẹgbọn bọsẹ
- 4. 4. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo.. ẹni tí inú rẹ dùn bí se ka ìwé ibeere idanwo ni..........
A) Bọla B) Dupẹ C) Bọsẹ D) Ẹgbọn bọsẹ
- 5. 5. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo...tani o sọ pe ohun dáràn ninu yara idanwo
A) Ẹgbọn bọsẹ B) Dupẹ C) Bọsẹ D) Bọla
- 6. 6.ninu iwe alawiiye akọle ọwọ ẹyin....iye awọn orukọ orisirisi ti a pè owo ẹyin nínú ẹkọ yìí jẹ
A) Mẹfa B) Mewa C) Meje D) Marun
- 7. 7. Nínú ìwe alawiiye akọle owo ẹyin... Ọkan nínú awọn nkan ti awọn eniyan n fi dipò owó abẹtẹlẹ ni
A) Igberaga B) Faari C) Ara wọn D) Suuru
- 8. 8. Gbólóhùn alabọde ni a tún mọ Si......
A) Alakanpọ B) Ọlọpọ ọrọ ise C) Aṣẹ D) Ẹlẹyọ ọrọ ìse
- 9. 9. Àpẹẹrẹ ọrọ ìse yii.(..........) Le duro' gẹgẹ bí gbólóhùn alabọde
A) Jade B) Si C) Na D) Jẹ
- 10. 10. Ẹni tabi ohun tí o se nnkan nínú gbólóhùn ni.........
A) Oluwa B) Ẹpọn C) Ẹyàn D) Abọ
- 11. 11. ........ Ni ẹni tabi ohun tí a ṣe nnkan Si nínú gbólóhùn
A) Ẹyàn B) Ẹpọn C) Abọ D) Oluwa
- 12. 12. ......... Ni a mọ sì ọrọ tabi atopọ tí o n gbé oye tabi ero kíkún jade
A) Lẹta B) Gbólóhùn C) Silebu D) Ọrọ ise
- 13. 13. Adirẹsi mélòó ni lẹta gbẹfẹ ni
A) Meji B) Mẹrin C) Ọkan D) Mẹta
- 14. 14. Lẹta...... Kí i ni akọle
A) Aigbagbẹfẹ B) Aṣẹ C) Gbẹfẹ D) Iroyin
- 15. 15. Ọwọ........ Ni adirẹsi ma n wa
A) Ẹyin B) Ọtun C) Iwaju D) Osi
- 16. 16. Ipin mélòó ni lẹta Pin si
A) Mẹta B) Meji C) Merin D) Marun
- 17. 17. ......... Ni ọna àròkọ ti a ma n Gba sọ ohun to wa nínú wa Si ẹlòmíràn yala boya ololufẹ ẹni tabi òbí ẹni tabi ọgá ile isẹ kan
A) Ọrọ B) Gbólóhùn C) Silebu D) Lẹta
- 18. 18. Ọrẹ mí ọwọn jẹ.............nínú lẹta gbẹfẹ
A) Inifẹ ẹni B) Ipọnni C) Ibuni D) Ìkíni
- 19. 19. ...... lẹta ti aa n kọ Si awọn ènìyàn ti wọn wa ni ipò kan ni ibi isẹ aladani tabi Si àjọ ilu
A) Iroyin B) Aigbagbẹfẹ C) Gbẹfẹ D) Aṣẹ
- 20. 20. Lara awọn ti a ma n kọ lẹta aigbagbẹfẹ Si ni awọn wọnyi ayafi....
A) Olootu ìwe iroyin B) Alága ìjọba ìbílẹ̀ C) Ololufẹ ẹni D) Giwa ile isẹ
- 21. 21. Adirẹsi mélòó ni lẹta aigbagbẹfẹ ma n ni
A) Ẹyọkan B) Mẹta C) Mẹrin D) Meji
- 22. 22. Kínní 195 ni èdè yorúbá
A) Meedofa B) Ọgọwa C) Marunlenigba D) Marundinigba
- 23. 23.bawo ni ase lé pe figọ yìí lede yorúbá 170
A) Ọgọsan B) Ọgọwa C) Aadọwa D) Aadọsan
- 24. 24. Aadọwa ni figọ jẹ....
A) 200 B) 190 C) 170 D) 160
- 25. 25. Orukọ miran fún ọgọwa ni....
A) Okanlelọgọfa B) Ọkanlaadofa C) Igba D) Ọdunrun
- 26. 26. Ìtumọ lẹta gbẹfẹ ni ede gẹẹsi ni...
A) Package letter B) Informal letter C) Formal letter D) Semi formal letter
- 27. 27. Ìtumọ gbólóhùn alabọde ni èdè gẹẹsi ni.......
A) Compound sentence B) Complex sentence C) Compound complex sentence D) Simple sentence
- 28. 28. Ìtumọ gbólóhùn alakanpọ ni èdè gẹẹsi ni..........
A) Compound complex sentence B) Complex sentence C) Simple sentence D) Compound sentence
- 29. 29. Ìtumọ lẹta aigbẹfẹ ni èdè gẹ̀ẹ́sì ni.........
A) Informal letter B) Semi formal letter C) International letter D) Formal letter
- 30. 30. 99 ni onka yoruba jẹ........
A) Ọkandinladọrun B) Ọkandinlọgọrun C) Ọkanlelọgọrun D) Ọkanlelaadọrun
|