- 1. 1. Nínú ìwe alawiiye, (akọle : ogun idanwo)tani o mu awọn ọmọ lọ sì ile onisegun
A) Ẹgbọn bọsẹ B) Dupẹ C) Bọsẹ D) Bọla
- 2. 2. Nínú akole ogun idanwo ìwe alawiiye...awọn wo ni wón ro pe awọn yóò gbà gbogbo maaki tan
A) Bola B) Tolani C) Bọsẹ ati dupẹ D) Ẹgbọn Bola
- 3. 3.ninu iwe alawiiye akọle ogun idanwo..Ta ni kogba pe ogun idanwo n bẹ
A) Ẹgbọn bọsẹ B) Ṣeṣan C) Bọla D) Dupẹ
- 4. 4. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo.. ẹni tí inú rẹ dùn bí se ka ìwé ibeere idanwo ni..........
A) Bọla B) Dupẹ C) Bọsẹ D) Ẹgbọn bọsẹ
- 5. 5. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo...tani o sọ pe ohun dáràn ninu yara idanwo
A) Dupẹ B) Ẹgbọn bọsẹ C) Bọsẹ D) Bọla
- 6. 6.ninu iwe alawiiye akọle ọwọ ẹyin....iye awọn orukọ orisirisi ti a pè owo ẹyin nínú ẹkọ yìí jẹ
A) Marun B) Mẹfa C) Mewa D) Meje
- 7. 7. Nínú ìwe alawiiye akọle owo ẹyin... Ọkan nínú awọn nkan ti awọn eniyan n fi dipò owó abẹtẹlẹ ni
A) Igberaga B) Ara wọn C) Suuru D) Faari
- 8. 8. Gbólóhùn alabọde ni a tún mọ Si......
A) Ẹlẹyọ ọrọ ìse B) Alakanpọ C) Ọlọpọ ọrọ ise D) Aṣẹ
- 9. 9. Àpẹẹrẹ ọrọ ìse yii.(..........) Le duro' gẹgẹ bí gbólóhùn alabọde
A) Si B) Na C) Jẹ D) Jade
- 10. 10. Ẹni tabi ohun tí o se nnkan nínú gbólóhùn ni.........
A) Abọ B) Ẹyàn C) Ẹpọn D) Oluwa
- 11. 11. ........ Ni ẹni tabi ohun tí a ṣe nnkan Si nínú gbólóhùn
A) Oluwa B) Ẹyàn C) Ẹpọn D) Abọ
- 12. 12. ......... Ni a mọ sì ọrọ tabi atopọ tí o n gbé oye tabi ero kíkún jade
A) Ọrọ ise B) Silebu C) Gbólóhùn D) Lẹta
- 13. 13. Adirẹsi mélòó ni lẹta gbẹfẹ ni
A) Mẹrin B) Meji C) Mẹta D) Ọkan
- 14. 14. Lẹta...... Kí i ni akọle
A) Gbẹfẹ B) Aigbagbẹfẹ C) Iroyin D) Aṣẹ
- 15. 15. Ọwọ........ Ni adirẹsi ma n wa
A) Ẹyin B) Ọtun C) Iwaju D) Osi
- 16. 16. Ipin mélòó ni lẹta Pin si
A) Meji B) Merin C) Marun D) Mẹta
- 17. 17. ......... Ni ọna àròkọ ti a ma n Gba sọ ohun to wa nínú wa Si ẹlòmíràn yala boya ololufẹ ẹni tabi òbí ẹni tabi ọgá ile isẹ kan
A) Lẹta B) Silebu C) Gbólóhùn D) Ọrọ
- 18. 18. Ọrẹ mí ọwọn jẹ.............nínú lẹta gbẹfẹ
A) Ipọnni B) Inifẹ ẹni C) Ibuni D) Ìkíni
- 19. 19. ...... lẹta ti aa n kọ Si awọn ènìyàn ti wọn wa ni ipò kan ni ibi isẹ aladani tabi Si àjọ ilu
A) Aigbagbẹfẹ B) Gbẹfẹ C) Aṣẹ D) Iroyin
- 20. 20. Lara awọn ti a ma n kọ lẹta aigbagbẹfẹ Si ni awọn wọnyi ayafi....
A) Ololufẹ ẹni B) Olootu ìwe iroyin C) Alága ìjọba ìbílẹ̀ D) Giwa ile isẹ
- 21. 21. Adirẹsi mélòó ni lẹta aigbagbẹfẹ ma n ni
A) Meji B) Mẹta C) Mẹrin D) Ẹyọkan
- 22. 22. Kínní 195 ni èdè yorúbá
A) Marundinigba B) Ọgọwa C) Marunlenigba D) Meedofa
- 23. 23.bawo ni ase lé pe figọ yìí lede yorúbá 170
A) Ọgọwa B) Aadọwa C) Ọgọsan D) Aadọsan
- 24. 24. Aadọwa ni figọ jẹ....
A) 170 B) 160 C) 200 D) 190
- 25. 25. Orukọ miran fún ọgọwa ni....
A) Okanlelọgọfa B) Ọkanlaadofa C) Igba D) Ọdunrun
- 26. 26. Ìtumọ lẹta gbẹfẹ ni ede gẹẹsi ni...
A) Informal letter B) Semi formal letter C) Package letter D) Formal letter
- 27. 27. Ìtumọ gbólóhùn alabọde ni èdè gẹẹsi ni.......
A) Compound complex sentence B) Simple sentence C) Compound sentence D) Complex sentence
- 28. 28. Ìtumọ gbólóhùn alakanpọ ni èdè gẹẹsi ni..........
A) Compound sentence B) Simple sentence C) Complex sentence D) Compound complex sentence
- 29. 29. Ìtumọ lẹta aigbẹfẹ ni èdè gẹ̀ẹ́sì ni.........
A) Informal letter B) Formal letter C) International letter D) Semi formal letter
- 30. 30. 99 ni onka yoruba jẹ........
A) Ọkanlelọgọrun B) Ọkandinlọgọrun C) Ọkandinladọrun D) Ọkanlelaadọrun
|