ThatQuiz Test Library Take this test now
AIC Yoruba JSS 1 first term Exam 2024
Contributed by: College
  • 1. 1. Tani babanla awon yorùbá
A) Asara
B) Orangun
C) Oduduwa
D) Lamurudu
  • 2. 2. Alifabeeti ede Yoruba je......
A) Mejila
B) Meedogbon
C) Meedogun
D) Merinla
  • 3. 3. ........... Ni iro ti ape nigba ti idiwo kosi fun eemi
A) Konsonanti
B) Mofiimu
C) Faweli
D) Silebu
  • 4. 4.Onka faweli arin je....
A) Meji
B) Meta
C) Marun
D) Merin
  • 5. 5.Onka faweli ni akotan je.....
A) Marun
B) Mefa
C) Meje
D) Merin
  • 6. 6.Onka konsonanti ni akotan je.....
A) Meedogbon
B) Metala
C) Merinla
D) Mejidinlogun
  • 7. 7.Ti aba lo ipo tan_ an_na ofun, ale pin konsonanti si orisi ona......
A) Meji
B) Mefa
C) Marun
D) Meta
  • 8. 8 Ti aba lo ibi isenupe ale pin konsonanti si ona......
A) Mejo
B) Mewa
C) Meje
D) Marun
  • 9. 9 Awon leta aferigipe ni .....
A) J,s
B) F
C) t,s,d,n,r,j
D) K,g
  • 10. 10. m,n. je leta
A) Afunpe
B) Airanmupe
C) Aferigipe
D) Aranmupe
  • 11. 11. Oruko Omo oduduwa ni.....
A) Alaketu
B) Okanbi
C) Oba ibini
D) Oranmiyan
  • 12. 12. Yoruba gbagbo pe oduduwa ati awon eniyan baba re fi ............ rin lati Meka de ile_ ife
A) Aadofa ojo
B) Aadoje ojo
C) Aadorun ojo
D) Ogorun ojo
  • 13. 13. Tani won Koko fi je oba akoko ni ile _ ife
A) Buremo
B) Oduduwa
C) Asara
D) Lamurudu
  • 14. 14. ........ Ni otedo si ilu ketu
A) Alaketu
B) Oranmiyan
C) Onisabe
D) Olupopo
  • 15. 15. Oranmiyan tedo si ilu.......
A) Ila
B) Owu
C) Ketu
D) Oyo
  • 16. 16. Tani abikeyin awon Omo _ Omo oduduwa
A) Oranmiyan
B) Olupopo
C) Orangun
D) Onisabe
  • 17. 17. Tani akobi awon Omo _ Omo oduduwa
A) Onisabe
B) Olowu
C) Orangun
D) Oranmiyan
  • 18. 18. Orisi isori Oro melo lowa ninu ede yoruba
A) Meje
B) Mefa
C) Mejo
D) Mesan
  • 19. 19. .......... Ni awon oro ti won le daduro ni ipo oluwa, abi abọ tabi eyan ninu gbolohun
A) Oro oruko
B) Oro eyan
C) Oro atokun
D) Oro ise
  • 20. 20. ........... Je oluse isele inu gbolohun
A) Atokun
B) Eyan
C) Abo
D) Oluwa
  • 21. 21. .......... Ni olufaragba nnkan ti oluwa se ninu gbolohun
A) Eyan
B) Abo
C) Atokun
D) Oluwa
  • 22. 22. ....... Lowa ni ipo oluwa ninu gbolohun yii... Bola losi ilu amerika
A) Losi
B) Amerika
C) Bola
D) ILu
  • 23. 23. Apere Oro oruko ni ipo abo ninu gbolohun yii.. ogbeni Abdul afeez na akeeko bi eran
A) Akeeko
B) Eran
C) Ogbeni
D) Abudul afeez
  • 24. 24 ........ Ni awon ti an lo dipo oro_ oruko ninu gbolohun
A) Oro oruko
B) Oro ise
C) Oro atokun
D) Oro aropo oruko
  • 25. 25. Apere Oro aropo oruko ninu gbolohun yii.... O Ra iwe
A) Ora
B) Iwe
C) O
D) Ra
  • 26. 26. Melo ni abuda Oro aropo oruko
A) Marun
B) Merin
C) Meta
D) Mefa
  • 27. 27. Melo ni Oro aropo afara joruko
A) Merin
B) Marun
C) Meta
D) Mefa
  • 28. 28. Onka Konsonanti airanmupe je....
A) Merindinlogun
B) Metala
C) Merinla
D) Mejila
  • 29. 29. Onka faweli iwaju je.....
A) Merin
B) Meta
C) Marun
D) Meji
  • 30. 30. Onka konsonanti akunyun je ......
A) Merinla
B) Mejila
C) Mokanla
D) Metala
  • 31. 31. Kọnsonanti aikunyun ni
A) G
B) Gb
C) B
D) Ṣ
  • 32. 32. Iro fawẹẹli ní...
A) B
B) F
C) A
D) L
  • 33. 33. Ẹsin akọkọ ti wọn sìn Ni ilu mẹka ni ẹsin
A) Musulumi
B) Guru
C) Iborisa
D) Kisitẹni
  • 34. 34. ...... Ni olori awọn eniyan bá ni ile - ifẹ
A) Lamurudu
B) Agunlejika
C) Agbọnmiregun
D) Ọba ibini
  • 35. 35. Ipinlẹ melo ni iran yoruba wa ni naijiria
A) Meje
B) Mẹsan
C) Mẹwa
D) Marun
  • 36. 36. 100 ni onka yoruba jẹ
A) Ogoje
B) Ọgọrun
C) Aadọrun
D) Ogoji
  • 37. 37. Ọrọ orukọ ninu gbólóhùn yìí nì...mo jẹ ẹwa lamulukẹ sun lalẹ ana
A) Lamulukẹ
B) Ẹwa
C) Mo
D) Ana
  • 38. 38. Alifabẹẹti ede Yorùbá Pin Si ọna....
A) Meji
B) Meje
C) Mẹta
D) Marun
  • 39. 39. Agbalagba jẹ ọrọ oni silebu...
A) Meje
B) Meji
C) Marun
D) Mẹrin
  • 40. 40. ...... Ni o ṣiṣẹ ẹyàn nínú gbólóhùn yìí....ile iwosan ni Shola wa
A) Ile
B) Iwosan
C) Ni
D) Shola
Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.